Home / Àṣà Oòduà / Won ti se idajo Sharia fun alagbere obirin

Won ti se idajo Sharia fun alagbere obirin

Obirin yii ni won ti se idajo Sharia fun ni orileede Indonesia latari wi pe, gbogbo igba lo n tele okunrin kan eleyii ti kii se oko re.
Awon kan tile tun jeri wi pe, oseese ki maanu naa ti maa “kerewa” arabirin naa ni koro eleyii to tako ofin orileede Indonesia. Olayemi Oniroyin tun rigbo wi pe, oko arabirin naa kii fi gbogbo igba gbele eleyii lo fun obirin naa ni anfaani lati ma tele ale re kiri igboro nigbogbo igba. Oun ati okunrin, ale naa ni won jo dana iya fun niwaju mosalaasi Baiturrahim to wa Banda Aceh ni orileede Indonesia.


About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

seun kuti

Orí kó Seun Kuti yọ kúrò lọ́wọ́ ikú ní yàrá ìgbàlejò US

Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han. Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika. Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, ...