
Erin ayo lenu gomina Abiola Ajimobi nigba ti won pe e lori ago wi pe o ti feyin Adewolu Ladoja janle nile ejo. Gomina Abiola Ajimobi ni ile ejo ti n risi awuyewuye eto idibo gomina ti da lare eleyii to waye lojo Isegun, ana ode yii.


Tagged with: Ajimobi
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
