Home / Àṣà Oòduà / Akiyesi Pataki

Akiyesi Pataki

Arákùnrin oníṣègùn oyinbo tó jẹ́ ọmọ bíbí Nigeria to wá n’ilu USA, fi ọrọ ìyànjú yí ranṣẹ fún anfaani ara wa. Jọ̀wọ́ ká, kí ó sì mú lo fún ìtọ́jú ara rẹ. Dr. A. Malgwi

Ọna ti àwọn ọdọ wá lóde òní, ngba ni àìsàn kidirin jẹ ohun tó ndẹru báni. Mo nfi itẹjade yí ranṣẹ torí kò le ràn wá lọ́wọ́ nínú ewu àìsàn kidirin.
Jọ̀wọ́ fara balẹ láti ka ọ̀rọ̀ ìsàlẹ̀ yí:

AKIYESI PATAKI

  • KIDIRIN WA GBA ÀMÓJÚTÓ TÓ PÉYE

Bí ọjọ́ méjì sí ìgbà tá wá yí, ní a gbọ ìròhìn ikú ọkàn ni àwọn òṣeré ori itage ọmọ ilẹ̀ wá ti àìsàn kidirin ṣekú pá.
Bakanna, Minister alabojuto Iṣẹ́, Honourable Teko Lake wá nílé ìwòsàn ni ẹsẹ kan ayé, ẹsẹ kan ọrùn, nítorí àìsàn kidirin yí na ni. Idanilẹkọ yi dá lórí bí a ṣe lè toju ara wa ti ao ni bá wọn nipin ninu àìsàn kidirin yí.

EYI NI ONA MẸ́FÀ PATAKI TI ÀÌSÀN KIDIRIN FI ŃṢE ENIYAN

  1. Dídá itọ mọ àpò itọ fún ìgbà pipẹ lai tọ, jẹ́ ọ̀nà àkọ́kọ́ tí ó má ń fà àìsàn kidirin. Tí ile itọ wá bá ń kùn ju bó ṣe yẹ lọ, o má nba ilé itọ wá jẹ́. Itọ yí tí ao tọ jáde nílé itọ wá, kún fún ọpọlọpọ kòkòrò aifoju ri ti a n pe ni bacteria, ti wọn ba npẹ ju nílé itọ wá, wọ́n má npọ sì ni kíákíá. Èyí má fún àwọn kokoro yí lanfani láti máa padà sínu kidirin wá àti àwọn ọ̀nà miran ti wọn lé gba jáde, eyi má ńṣe jamba fún kidirin wá púpò. Nígbà miran, àwọn kòkòrò yí ni ó má nfa aisan atọsi ọlọyun àti orisirisi àwọn aisan bí nephritis àti uremia. Tí itọ bá gbọn wá, kí a tọ itọ yí lásìkò tó yẹ.
  2. Jíjẹ iyọ pupọ ju, tún jẹ́ ọna miran ti àìsàn kidirin fi ń mú wá. Ao gbudọ jẹ́ iyọ ju ìwọ̀n 5.8 grams lọ ní ijoko ẹkan ṣoṣo.
  3. Jijẹ ẹran pupọ ju. Èròjà protein to wá nínú ẹran, to ba pọ ju má npa kidirin wá lára. Kí èròjà protein ṣe ń kuro lára ẹran tí a ń jẹ, bẹ ní kemika ammonia na ma ń jáde pẹlu rẹ. Kemika ammonia yí ko ni ìwúlò kankan lára. Tí ammonia yí bá ti ń poju bó ṣe yẹ lọ, ó má ńṣe àkóbá fún kidirin wá. Jíjẹ ẹran pupọ ju má njẹ ki ammonia yí po jù nínú kidirin wá ti yio ba kidirin wá jẹ́.
  4. Mímú kafini pupọ ju. Kafini jẹ́ lára àwọn èròjà tí ó má nwa nínú àwọn minira bí Coca-Cola, nescafe tea àti òbí tí a njẹ. Kafini má njẹ ki ifunpa wá (blood pressure) ga ju bó ṣe yẹ lọ. Tí ifunpa wá bá nga ju, ó má ń ṣàkóbá fún kidirin wá. Torinaa, ẹ jẹ ki a sá fún mímú minira bí coke ati mimu nescafe pupọ ju àti jíjẹ òbí pupọ ju.
  5. Áìmu omi dada. Kidirin wá nílò omi láti ṣíṣe daradara, tí a kò bá mú omi daradara kidirin wá má ń ṣíṣe afipa ṣe àti wipe àwọn ìdọ̀tí (Toxins) tí kidirin wá yẹ kó sẹ kúrò nínú ẹ̀jẹ̀ wá, yio tun padà sára wá. Nítorí náà, ẹ jẹ ki a ma mu omi daradara, o kere ju kí a má mu omi pure water mefa lojumo. Ọ̀nà tó rọrùn láti mọ bóyá a ń mú omi to boti yẹ. Wò awọ itọ tó ń tọ bóyá ó pọn tàbí ó mọ bí omi. Tí ó bá pọn, ó kí mu omi tó. To ba mọ, ó nmu omi tó.
  6. Áìbìkítà láti ṣe ìtọ́jú aisan tó bá ńṣe wá lásìkò àti botiyẹ. Ẹ jẹ ki a ma tètè bójú tó àìsàn tó bá ńṣe wá lásìkò àti botiyẹ. Ẹ má ṣe ayẹwo ara wa nípa lílo àwọn ẸRỌ IFUNPA, ẸRỌ ITỌ SUGAR, ki a ma lọ rí dókítà wá lore kórè. Kí a má lo àwọn ogún wá nígbà tó yẹ. Ẹ jeki a rán ara wa lọ́wọ́. Ọlọ́run a ra wá lọ́wọ́ àti àwọn ẹbí wá lọwọ orisirisi àìsàn.

Ẹ̀JẸ̀ KÍ A SA FUN ÀWỌN OGUN WỌNYI WỌ́N ŃṢE ÌPALÁRA FUN ARA WA, WON JE OGUN TÓ LEWU GIDI GAN-AN.
*D-cold
*Vicks Action-500
*Actified
*Coldarin
*Cosome
*Nice
*Nimulid
*Cetrizet-D
Àwọn ogún yí ni èròjà Phenyle Propanol-Amide PPA. Èyí má nfa àìsàn rọparọsẹ(STROKE). Àwọn ogún yí ni ìjọba USA kò gbà láyé nilẹ wọn.

Jọ̀wọ́, kí ó tó pá ìtẹ́ jáde yí rẹ, rán ọrẹ rẹ lọwọ nípa fífi ìtẹ́ jáde yí ranṣẹ si. Nípa ṣíṣe bayi, ó lè ràn ẹnikan lọwọ. Fi ranṣẹ sì ọpọlọpọ ènìyàn..

Àwọn dókítà ni ilu United States tí ṣe àwárí àìsàn jẹjẹrẹ kan tó ndamu ọmọ ènìyàn lamu, ohun tó ń ṣokùnfà àìsàn yì ni èròjà kan tí a npe ni Silver Nitro Oxide. Silver Nitro Oxide ni kemika tí wọ́n fi bo nọmba tó wà lára Recharge card, tí a bá ra recharge card, e ma fi ekana ha kemika yí tí ó lè fà àrùn jẹjẹrẹ yí. Ṣé alábàápín atẹjade yí pẹlu awọn olólùfẹ́ rẹ.

ÌRÒHÌN ÌLERA TÓ ṢE PÀTÀKÌ

  1. Gba ìpè lórí fóònù rẹ sì etí osi.
  2. Má ma lo ogún òní horo pẹlu omi tutu.
  3. Má ma jẹ onjẹ to wúwo lẹhin ago marun irọlẹ.
  4. Mú omi daradara lowurọ, mú omi niwonba lalẹ.
  5. Àkókò to dára jù fún orun sísun ju ni àgó mẹwa alẹ sì àgó mẹrin arọ.
  6. Ó kò gbọ́dọ̀ sún ni kété tí ó bá lo ogún tàbí jẹun tán.
  7. Tí agbára batiri fóònù rẹ bá ti kú ìlà kan, ó kó gbọ́dọ̀ gba ìpè, torí wipe, àwọn agbára aifoju tí fóònù rẹ má nto ìlọ́po 1000 tí ole ṣe àkóbá fún ìlera rẹ.

Ǹjẹ́ ole fi ite jáde yí ranṣẹ sì àwọn ènìyàn tí ó bìkítà fún?
Èmi ti ṣe bẹ.
Anu ṣíṣe ó nan wa lowo ṣùgbọ́n imọ jẹ agbára.

About ayangalu

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo