Home / Àṣà Oòduà / Arákùnrin tí ó jé omo Ebonyi, ìpínlè kan ní orílè èdè Nìjíríà yí ti kú sí ilè Italy pélù àwon mókànlá míràn.

Arákùnrin tí ó jé omo Ebonyi, ìpínlè kan ní orílè èdè Nìjíríà yí ti kú sí ilè Italy pélù àwon mókànlá míràn.

Èyí bani ní inú jé púpò, arákùnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà yí ti kú pèlú àwon mókànlà míràn ní inú ìjàmbá okò tí ó selè ní Foggia ní ilè Italy.

Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé yí, orúko rè a máa jé Mr.Roman Mgbeke láti ìpínlè Ebonyi, tí ó lo sí ibi isé pèlú àwon mókànlá míràn tí kú sùgbón tí won sàgbákò ìjàmbá okò tí méjìlá sì kú nínú won .

Àwon ebí rè kò tí gbó ìsèlè yí, e jòwó e báwa pín àwòrán yí tí won yóò fi ri.

About Awo

One comment

Leave a Reply to OLALUSI OLATUNJI T Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?