Home / Àṣà Oòduà / El- Rufai bá e̩bí ènìyàn 51 ké̩dùn

El- Rufai bá e̩bí ènìyàn 51 ké̩dùn

El- Rufai bá e̩bí ènìyàn 51 ké̩dùn
Nnkan buruku sele ni ilu Giwa ati Igali ni oru ojo aiku moju ojo Aje.
Awon adihamora ni won tun ya bo awon ilu ati abule ni ipinle Kaduna ti won si bere si pa awon eniyan ibe, won si tun dana sun ile ati awon nnkan ini won miiran.

Gomina ipinle naa, Nasir El- Rufai se abewo si awon ilu naa lonii, o si ba won kedun gidi nipa awon emi to sonu.
Aare Mohammadu Buhari naa ranse ibani kedun si ipinle naa nipa awon eniyan ti won padanu.

Ki Eledua ba wa dawo aburu duro.

Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

About ayangalu

x

Check Also

ÌKéde ní Yàjóyàjó láti Ilẹ̀ ÌJẹ̀ṣà

Ìkéde ní Yàjóyàjó láti Ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà

Ní ìtẹ̀síwájú orò ìwúyè Ọwá Obòkun Àdìmúlà ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, Ọwá Clement Adésuyì Haastrup, wọ́n ti kéde ìṣéde jákèjádò ìlú Iléṣà. Gẹ́gẹ́ bí Olóyè Àgbà Ọlálékan Fọ́lọ́runṣọ́ tí wọ́n jẹ́ Loro ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà ṣe kéde, ìṣéde náà yóò bẹ̀rẹ̀ ní aago mẹ́jọ alẹ́ òní Ọjọ́ Ẹtì, Ọjọ́ kọkànlá títí di aago mẹ́fà Òwúrọ̀ ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin (8pm of April 11 to 6am of April 12, 2025) Kí eku ilé ó gbọ́, kó sọ fún toko o!!! Gbogbo ènìyàn ...