Ènìyàn mó̩kàndínlógójì ti ní àsepò̩ pèlú alárùn coronavirus l’Ogun
Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí
Iberu bojo ti po gan-an ni ipinle Ogun bayii, paapaa julo lati igba ti ayewo ti fihan pe alarun buruku kan ti wo orileede yii lati orileede Italy.
Lati igba naa ni ijoba ti bere si nii se iwadii gbogbo ibi ti arakunrin naa de ki o to di pe aisan naa daa gunle.
Won ni ilera ti yara n sele si arakunrin naa, amo ayewo to gbopan gbodo waye pelu awon to ba se ipade ni Ewekoro to wa ni ipinle Ogun.
Won ni ayewo gbodo wa pelu eni to fi moto gbee lati papako ofurufu, won ni ayewo gbodo waye lori awon ti won jo wo baalu de ipinle Eko ati bee bee lo.
Elegbe gbogbo ipinle ni o ti gbaruku ti imurasile arun buruku naa ki o maa baa ba won ni ojiji. Iwadii ko tii fihan boya awon eniyan yii ti ko arun tabi won ko koo.