Home / Àṣà Oòduà / Fúlàní darandaran pa àwon èèyàn ní ojú ònà Makarda ní òpópónà Makarda.

Fúlàní darandaran pa àwon èèyàn ní ojú ònà Makarda ní òpópónà Makarda.

Óní òun so gbangba gbàngbà ni Láì bèrù enikéni :báyìí ni Adamu Donald Dekwagh, wípé enikéni kò gbodò sùn nígbà tí igbákejì Ààre orílè èdè lo kí won ní Benue ní ànà yí tí àwon wòólì méjì àti darandaran pa. Óní àwon Fúlàní darandaran ti di p’àyàn p’àyàn.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...