Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tokotayà yí ti won pàdé nígbà tí won ń sin orílè èdè won lówó ní odún mérin séyìn.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tokotayà yí ti won pàdé nígbà tí won ń sin orílè èdè won lówó ní odún mérin séyìn.

Arábìnrin Nìjíríà kan tí a mò sí Rosemary nípa eni tí yó sèsè di oko rè Láìpé odún màrún-ùn séyìn, nígbà tí won ń sin orílè èdè won lówó ní Kaduna ti pín àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.

Wón dìjo wo aso ìsìnlú won pèlú bàtà aláwò kan náà.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?