Don't Miss
Home / Àṣà Oòduà / Hannah Idowu Dideolu Awolowo Ti Lo Ba Oko Re Lorun

Hannah Idowu Dideolu Awolowo Ti Lo Ba Oko Re Lorun


Won ti bere igbaradi, inu osu kokanla odun yii ni won pinnu lati se ojo ibi Ogorun (100) Odun Yeye Oodua. Sugbon iku seka, iku doro, iku mu Hannah Idowu Dideolu Awolowo lo leni odun mokandinlogorun (99).   Ki Edua oke ba wa tete mama si afefe rere. Ase !

Orisun:

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*