Home / Àṣà Oòduà / Iyalenu: Foto Ohun To N Sele Ni Ibudo Awon Ti B’Haram So Di Alailara, Alaini Nnkankan Niyii

Iyalenu: Foto Ohun To N Sele Ni Ibudo Awon Ti B’Haram So Di Alailara, Alaini Nnkankan Niyii


Ibudo awon eniyan ti Boko Haram So di alailara ati alainile lori latari ijamba ati ikolu Boko Haram ni yii ni Maiduguri to wa ni Ipinle Borno.

E le biliifu wi pe sobiri ti won fi n re ile ni won fi n bu ounje fun awon omo eniyan.

Ki Edumare ba wa mu fitinati kuro lorileede Naijeria.
Ase

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára