Home / Àṣà Oòduà / Milionu Mefa Ti Gbe Omo Naijeria Wonu Ese-Mefa: Ojukokoro Ti Pa Chukwudi!

Milionu Mefa Ti Gbe Omo Naijeria Wonu Ese-Mefa: Ojukokoro Ti Pa Chukwudi!


Chukwudi, omo odun mejidinlogbon (28)ti padanu emi re leyin igba to ta kidinrin re ni milionu mefa owo naira (N6million)niluu Malaysia

Chukwudi la gbo wi pe o tirafu lati ilu re, Owerri, ipinle Imo lati lo siluu Malaysia nibi to ti lo ta kidirin re fun okan lara awon olowo ilu naa ti won niilo re fun ilera ti won.

Gege bi iwadii awon oniroyin lati owo awon omo Naijeria to wa niluu Malaysia. Won ni Chukwudi ko ni eni akoko ti yoo wa si ilu Malaysia lati wa ta kidinrin re, aimoye awon omo Naija ni won se e.

O ni pupo awon omo Naijeria feran lati wa si Malaysia lati wa ta kidinrin won latari owo goboi ti won maa san fun won eleyii ti o mu won di olowo ojiji leyin ti won ba fi kidirin won sile tan.

Chukwudi ti ku bayii, milionu mefa ko si ni ba wonu ese-mefa lo. Ta a wa ni yoo na milionu mefa leyin ti Chukwudi ti wonu ese-mefa lo?

 

Iroyin èdè oyinbo (English Version)

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

tems

Mo setán láti kú’ – Tems

Mo setán láti kú’ – Tems Mary Fágbohùn Olorin Naijiria olugbafe eye Grammy, Temilade Openiyi, ti a mo si Tems, ti safihan pe oun setan lati doju ko saare nigba ti oun fi eya orin takasufe ti gbogbo eniyan mo kaakiri orile ede sile fun R&B. Tems wi pe oun ni igbagbo pupo ninu ara oun to bee ti oun ko bikita bi oun o ba “je nnkankan tabi da enikeni” pelu R&B. Olorin ‘Essence’ naa so pe oun kan ...