Home / Àṣà Oòduà / Abiyamo Fi Omije Gbe Omo Re Sinu Koto

Abiyamo Fi Omije Gbe Omo Re Sinu Koto


Ipokipo ti eda ba wa laye, e pe ko maa dupe. Ibikibi ti ori ba da ni si ka fi ope fun Oluwa oba nitori awon kan ko tile ni ida kan ninu ogorun anfaani ti a ni.  Ebi n pa awon kan, kosi si ounje fun won rara. Ogun, wahala, rukerudo ati aibale okan ti so awon ilu kan sinu adawon ayeraye.   Foto yii lo lalewu lori ikanni Facebook, eleyii to n se afihan omobirin alaini, alailenikan, eni ti ko ri ounje je rara, nibi to ti n sin omo re sinu koto.

Orisun

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...