Home / Àṣà Oòduà / “Kini Idi Ti Fasola Fi Wu Ewu Funfun Lori Ko To Kuro Nijoba?” Ninu Iwe Iroyin Owuro Ni Idahun Naa Wa

“Kini Idi Ti Fasola Fi Wu Ewu Funfun Lori Ko To Kuro Nijoba?” Ninu Iwe Iroyin Owuro Ni Idahun Naa Wa


Akole gbagada to jade lati inu iwe Iroyin Owuro ti ose yii lo n so nipa ohun to faa ti Fasola fi wu ewu lori ko to pari ijoba re nigba ti awon akegbe re bi Mimiko ati Ajimobi n dan gbirin.

Awon akole mii to tun wa loju ewe akoko iwe Iroyin Owuro niyii:

*Omoge Mejilelaadota ti ko mokunrin ri se idije lEkoo

* Idi ti emi ati Tinubu fi daru- Gbenga Daniel

*Ni Akure, awon Omoota seruba Odunlade Adekola.

Ati awon iroyin mii to gbamuse.

E gbiyanju kee ra Iroyin Owuro, ogorun naira pere ni.

 

olayemioniroyin

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Sanwo olu

Ìpínlẹ̀ Eko ní ìfojúsùn ìpè pàjáwìrì ìsẹ́jú márùn-ún péré

Ìpínlẹ̀ Eko ní ìfojúsùn ìpè pàjáwìrì ìsẹ́jú márùn-ún péré Yínká Àlàbí Ile-iṣẹ Aṣẹ ati Iṣakoso Pajawiri ti Ipinle Eko sọ pe awọn ti setan lati dahun si awọn ipe pajawiri ni ipinlẹ Eko laarin isẹju marun-un pere.Olùdarí Àgbà fún ilé-iṣẹ́ náà, Ọ̀gbẹ́ni Femi Giwa, sọ èyí ní ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan pẹ̀lú awọn oniroyin ní ìlú Èkó.Giwa sọ pé àfojúsùn ilé-iṣẹ́ náà ni láti dín àkókò tó wà láàrín ìyè àti ikú kù nípa rírí dájú pé ìdáhùn náà wáyé láàrín ìṣẹ́jú ...