Home / Àṣà Oòduà / Oko Toyin Aimakhu, Adeniyi Johnson Ti Dale Ife

Oko Toyin Aimakhu, Adeniyi Johnson Ti Dale Ife

Laipe yii ni omobirin naa yo oruko oko re kuro ninu oruko re. Bakan naa ni awon eniyan tun kiyesi wi pe awon foto oko re to wa lori ikanni instagram re lo ti fe e gbonyo tan.

Adeniyi Johnson ti n be iyawo re bayii, o ni oun loun jebi ohun to n fa wahala laaarin awon mejeeji. E le ka alaye re nibi: http://www.facebook.com/photo.php?fbid=881199908632560&set=gm.1037407549643887&type=1

Awon kan ni oko re se asemase kan ni, isele naa si bi Alakada ninu pupo ju.

Awon eniyan kan ti n be Toyin wi pe ko maa binu, nigba ti awon kan n naka abuko si oko re ati gbogbo okunrin gege bi olojukokoro, to je wi pe gbogbo ejo ni jije lodo won.

E tun le ka ohun ti awon ololufe Toyin n so nibi: http://www.facebook.com/photo.php?fbid=881200005299217&set=gm.1037407549643887&type=1

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...