Ebora ilu Owu di Ebora agbaye: Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti
Aare ile Naijiria nigba kan ri, Olusegun Aremu Obasanjo baba Iyabo ni won ti yan bayii gege bi siamaanu igbimo egbe awon aare ti won ti feyinti agbaye, World Council of Ex- Presidents.
Itesiwaju tuntun to de ba Ebora ti ilu Owu yii ni a le gba wi pe o n jeri alaye re nigba kan, nibi to ti n se alaye ara re gege bi asaaju ile Naijiria, ile adulawo ati agbaye lapapo.
Obasanjo ti o ti fi igba kan je alaga egbe African Union ni won ti yan gege bi alaga eleekarun-un bayii fun igbimo egbe awon aare agbaye to ti feyin ti. Awon ti won de ipo naa saaju ni:
(1) Helmut Schmidt lati Germany
(2) Malcolm Fraser lati Australia
(3) Jean Chretien lati Canada ati
(4) Franz Vranitzky lati Australia
Orisun: http://www.olayemioniroyin.com/