Òrò tí ó gbòde kan ni wípé Chidinma Ekile ti darapò mó egbé burúkú àti wípé ó ti n kégbékégbé látàrí wípé ó ya tàtúù dí èyìn rè . Chidinma Ekile níbi ayeye kan tí ó wo aso tí ...
Read More »Arewà tí ó se ìgbéyàwó láì kun nkankan sí ojú ní ojó èye rè .
Èyin òdóbìnrin ; njé èyin le múra báyìí ní ijó ìgbéyàwó yín bí? Gbogbo obìnrin ni ó máa n gbèrò láti dàbí egbin ní ojó ìgbéyàwó won , gbogbo ònà ni won yóò sì wá láti jékí èróngbà won ...
Read More »Ìgbéyàwó ìbílè ti Oludamilola Osinbajo àti Oluseun Bakare ní Aso Rock.
Ìgbéyàwó ìbílè ti Oludamilola Osinbajo àti Oluseun Bakare ní Aso Rock. Èyí ni àwòrán láti òdò igbákejì Ààre, professor Yemi Osinbajo, omobìnrin rè Oludamilola Osinbajo níbi ìgbéyàwó ìbílè rè èyí tí ó wáyé ní ilé Ààre orílè èdè Nàíjíríà. Igbákejì ...
Read More »Ọ̀jọ̀gbón Akinwunmi Isola
Ọ̀jọ̀gbón Akinwunmi Isola ni wọn bí ní ọjọ́ kẹrìnlélọ́gún oṣù Ọ̀pẹ ọdún 1939 (24 December 1939) wọn jẹ́ òsèsé, ohun kọ̀wé, Oluṣiṣẹ nípa èdè Yorùbá. A mò wón sí kíkọ ìwé ni èdè Yorùbá, wón sì tún gbé èdè Yorùbá ...
Read More »A kú àmójúbà Osù Eréna (March) tuntun.
Osù ìdèra, ìtèsíwájú, ìse rere ni yóò jé fún gbogbo wa. Nínú Osù tuntun yìí, àìsàn kò níí jé ìpín enìkóòkan wa. Eni yòówù tí àìlera bá n dà láàmú, Olódùmarè yóò so ó dèrò. A kò níí rí ìjà ...
Read More »Àwon ológun orílè èdè Nàíjíríà ya àwòrán pèlú ejò rògbòdò léyìn tí won pa á tán .
Àwon ikò ológun ni inú won n dùn tí won sì n yò léyìn tí won pa ejò nla rògbòdò kan níbi tí won tèdó sí . Àwon Akoni yí ya àwòrán pèlú eranko afayàfà yí nígbà tí inú ...
Read More »Alágbárí òdómokùnrin kan tí a mò sí yahoo boy lo omo ègbón rè okùnrin tí kò ju omo odún méje lo láti fi se ògùn owó ní ìlú èkó .
Òdómokùnrin kan ni owó àwon agbófinró tè nígbà tí ó n lo omokùnrin ègbón rè láti fi se ògùn owó ní ìlú èkó. Gégé bí a se gbó, orúko òdómokùnrin tí a fi èsùn kan ni Tunde Owolabi ...
Read More »E wo nkan tí ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èkó tí a mò sí UNILAG se! Sé eléyìí kò ní jé kí àwon òdómobìnrin wa n’íìfé ohun afefe yèyè si báyìí.
Nígbà míràn kò ye kí á bá àwon òdómobìnrin wa tí won n’íìfé ohun ayé wí jù, nígbà tí ó jé wípé àwon àwùjo wa kò kúkú mú orí eni tí n se isé takuntakun wú. Ká sisé kára ...
Read More »Oko àti ìyàwó se ayeye ojó ìbí won nígbà tí won pé ogóòrún (100) àti márùndínlógóòrún papò.
Bàbá bàbá kan tí ó jé bàbá orílè èdè Nàìjíríà àti ìyá ìyá ni won se ayeye ojó ìbí fún nígbà tí won pé ogóòrún àti márùndínlógóòrún. Gégé bí olùsòrò kan lórí èro ayélujára se so àti olùsòrò gbogbogbò ...
Read More »Àwon tí won ti yo kúrò àti àwon tí won lé ní BBNaija ti se àyéwò sí ilé-ìfowópamó tí a mò sí Heritage bank.
Àwon Alábagbélé àti olùgbépò télè ti big brother Naija, àwon tí a mò sí Vandora, Princess, Dee one , Bitto àti àwon tí won lé kúrò Khloe àti k Brule se àbèwò sí ìkan lára àwon ilé-isé tí ...
Read More »