Home / Author Archives: ayangalu (page 49)

Author Archives: ayangalu

Orisa Alaase, Igbakeji Olodumare

Read More »

Odu Ifa Owonrin Alakara/ Ika

| |  | | | |   | | |   | | |   | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku isimi alayo loni eledumare yio funwa ni isimi to peye ...

Read More »

Oruko kan fu foto yi ?

Oruko kan fu awon arakurin yii  ?

Read More »

Aja To Rele Ekun To Bo..

Aja ti o ba rele ekun ti o si pada lai f’arapa ti iru aja be o si le gbegba ope olowo aja be ni yoo fi se ounje ajesun laipe ojo. KABIYESI ILU MOYE ni a o ba maa ...

Read More »

Oriki Ibeji

Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, ...

Read More »

Odu Ifa Owonrinwofun/ Ofun

| | | | | | | | | | | |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa ...

Read More »

‪#‎CelebratingOsun‬

Ladekoju Oore Yeye Osun o! E ku odun o! Osun Sengese Oyeyenimo a gbe wa o! Aase!   Photo Cc – Bekky Amusa

Read More »

Odu Ifa Owonrin Tutu/ Oturupon

| |  | | | |  | |  |     | | |   |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio gbo adura wa o yio si bawa tu ile aye to ...

Read More »

“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo….

“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo Wun ó bí’mo lé’mo n tó máalo Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo Bí Wón n n’íre lórun èmi ò mò Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo I will have enough ...

Read More »

Egbo talo daran egbaafa ninu awon mejeji ?

Alabahun (ijapa) lo re ile ana re oni ohun le so epa mefa di egbaafa ki odun to yipo, alabahun gbin epa tan ikun de’be o wu epa je ni ijapa ba ni ikun ti daran egbaafa. Ibeere talo daran ...

Read More »