Ope ni fun Olorun nitori ti o seun ti anu Re duro laelae. Mo layo lati so fun yin wipe Eledua fi Omo Tuntun Jojolo da ebi kan pataki ninu ilu yi lola. Tii se ebi Alhaja wa Adetunji Adenike ...
Read More »‘Yee! Yee!! Ni gbogbo n ke’
Basẹ ba mumi Omi a tan ninu asẹ, Bígèrè ba mumi Omi a tan ninu ìgèrè, ko tan ko tan lajá á lami; Ó tán n bí ò tàn? A ráta, a rata, ata kan ojú, ata n tani bi ...
Read More »Iwure Owuro: 16.05.2016
E MAA WI TELE MI : …… *Emi o ni fi aisan logba. *Iku aitojo ko ni pa mi. *Aye ko ni ta epo s’aso ala mi. *Ori olori ko ni ko ere ise mi. *Itansan ogo mi ko niku. ...
Read More »Fi Ti Okunrin Akonimogba(coach) Egbe Agbabolu Lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon
orewa! iwo nan ma ro ararepin, fi ti okunrin akonimogba(coach) egbe agbabolu lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon, toripe ORI TI YO DE ADE BOTI WU KORI KONI SE ALAIDE, atipe ILE ANU OLOHUN KI SU fun idi-eyi maso ireti nu ...
Read More »E Ase iwure yi ooo
Huunn Mose kabiyesi fun oba mi. Oba ajidara Oba toje dada owo e lowo. Iyi ti o da no nbe lowo eledumare Mo wa nbe o. Eledumare Jo o ma fiwa dara buruku o. Ma fun wa ni.omo abami eda. Oooo ...
Read More »Ebami Dasi Oroyii, aare orile ede Naijiria yii Muhamedu buhari…
eku ojumo gbogbo awa omo yoruba rere asikoyi atuwa lara ooooo Ase, ebami dasi oroyii, aare orile ede naijiria yii muhammedu buhari ti yowo yose kuro lori oro epo, epo tiwa di N145 per littre, sugbon eje karantipe nigbati ijoba ana ...
Read More »Gbolun kan fun baba oni bata yi
Eku dede asiko yi ooooo. E jo eyin omo ilu mi
Read More »Oruko Kan Fun Iya omode yii ?
Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?
Read More »Oro ton’lo Lowo bayi: E wo tomato timo ra ni 500 naira
Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni ...
Read More »Ibeere Toni: 15.05.2016
Nje Iwo leso “FACEBOOK PASSWORD” re fun Ololufere????? Huuum ema paro ooo
Read More »