Edakun, tani mo Oruko ti won pe Kokoro yi ?
Read More »Moki gbogbowa wipe aku ewu osu titun ti o wọle de wẹrẹ waba waa !
Mogbaladura wipe ogun aṣeti koni je tiwa ninu osu na,eni na tuni ọjọ (ẹtì) ti wonpeni (friday)…olodumare koni je ki akoju ogun aṣeti nile aye emi ati iwọ… Ẹni tikole tele,ẹniti wa ọmọ latibi,ẹni fe aṣerori lori adawole ẹ,ẹni todawọ ...
Read More »Otito lawo aiye, iro lagbele ro !
Owonrin omo ase’ka bi eni ti soo’to, Otito ba le di odo, ika bale di yangi, difa fun owonrin lojo tofe lo ya apo ika, E je kase otito, ka ya apo ika danu, Oore lope, ika koye omo Eniyan- ...
Read More »Oro kan se le si ore mi sugbon ko ye mi o!
O gba obinrin kan si le sugbon obinrin yi gbe omo lowo sugbon bi ki ore mi ofe lo se obinrin yi le yin osun meji oro won ti wo de bi pe bi won ba ti ri ara won ...
Read More »Yoo’ba loma n sope Igbin koni da enu dele….
Yoo’ba loma n sope Igbin koni da enu dele koma jifa ile Ifa owo ifa omo Ifa Alafia Ifa Ire Gbogbo kio wole to emin ati Iwo wa ! Ase !
Read More »Ewo lo lagbara ju ninu gbolohun wonyi lagbo ife ?
Moki gbogbo ile, e gbo ewo lo lagbara ju ninu gbolohun wonyi lagbo ife ? 1, o ti pari laarin emin ati iwo 2,odabo 3, min o ni ife re 4, mo ti un fe elomiran 5, ma pe ero ...
Read More »E fura ooo!!
Eyi ni lati sofun yin wipe anwa arakunrin kan ti oruko re nje Mukaila,ti o je onisowo eran maalu ni onibuore ni agbegbe iyana church ni ilu Ibadan. Arakunrin yi ni awon kan pe lati ori ero ilewo re lati ...
Read More »Oruko Kan fun Arakunrin ?
Otura alaketu/ Otura mele/ Otura owonrin !
1.Tooro toki Adifafun Alamala ketu,ekun ire lo n sun won ni ebo ni ko se,iya o si baba o si tooro toki ope gbigba ni o gba mi tooro toki. 2. Ewe le ole le alele le wure adifafun Orunmila ...
Read More »