Home / Author Archives: oodua (page 49)

Author Archives: oodua

Kini aleso nipa arakunrin yi?

Read More »

Ona wo ni won maa ngba siku agbalagba ode?

Ni kete ti agba ode kan ba rewaleasa ni awon akegbe re ninu ode yoo mura lati wa sinpa fun un.Eyi ma n waye fun oku lati yo ese re kuro ni agboole ati laaarin awon olode yoku ti won ...

Read More »

ORIKI ORILE IREMOGUN

Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni.Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ...

Read More »

Eyin eniyan mi e ba mi dahun ibeere miyi:

Bawo ni awon yoruba se nki awon wonyi: (1)Agbede. (2) Ondiri (3) Babalawo (4)Akope Ati Alaboyun

Read More »

Ti iya oko e ba se omo tie bayi kini wa so?

Read More »

Akuu dede asiko yii: Arakuriyii Lord lugard !

Arakuriyii ni. Lord lugard ohun loo so Nigeria papo. Ejowo se daada lose fun wa ni abi aida?

Read More »

Eyin Eniyan me, Iru Oruko wo loye fun Arakunrin yi

Read More »

Iru oruko wo la le fun eleyi

E bami fun Arakurin yi ni oruko!

Read More »

Kini kati pe eyi ooo

Read More »

Nje o le daruko ilu kan nile Yoruba to lewa to ilu eko ?

Read More »