Yinka Ayefele ti pada sile orin: Keresimesi odun yii ma minringindin Olayinka Joel Ayefele ti pada si yara agbara orin lati gbe orin tuntun jade fun awon ololufe re kari aye. Gege bi awon ololufe orin Gospel Tungba se mo, ...
Read More »Blog Page
Ambode naa ti pada si ni se bi Fayose: Gomina Eko ti pada sigboro aye
Gomina Akinwumi Ambode lo da awako akero kan ti n wa moto lona aito duro lonii nigboro Eko. Se kii se wi pe gomina naa fe ma se bi Ogbeni Ayodele Fayose?
Read More »Ojo-ibi oniroyin to gbamuse: Femi Davies, okunrin ogun
Oni ni ojo ibi Ogbeni Femi Davies, alase ati oludari MetroNews Nigeria. Igba odun, odun kan ni.
Read More »Omo yibo sepe fun Yoruba lori oro Biafra ti won fe da sile
Awon omo Yibo ti bere si ni soko oro si iran Yoruba to ri wi pe won fe pin kuro ninu orileede Naijiria. Won fe da Biafra sile, won ni awon ko ba Naijiria se mo. E dakun, e wo ...
Read More »Awon ologun yibon fun okan lara awon to pe fun Biafra ni Pota lonii
Leyin ti awon omo ologun yinbon pa okan lara awon oluwode ti won pe fun idasile Biafra, ibon tun ba okan lara won lonii niluu PORT HARCOURT.
Read More »Ilu Amerika gbalejo Goodluck Jonathan
Ilu Amerika ti gbalejo Aare ile Naijiria nigba kan ri, GOODLUCK JONATHAN si Challotsville to wa ni Virginia latari igbelaruge ijoba awarawa re ati gbigbe ijoba sile ni woorowo. Ogbeni Jonathan lo sokale siluu Amerika lojo aje ana. Lati Ọwọ ...
Read More »Lobatan: Won ti n ge tomato lori foonu chinco
Awon Yoruba ni ti ogun eni ba daniloju, eniyan fi i gbari ni. Ile ise China kan ti n se foonu, OUKITEL, ti kede wi pe, eni ba foju ana wo eegun, ebora nii boru won laso. Won ni to ...
Read More »Igo dudu meta: Toyin Aimakhu, Muyiwa Ademola ati Eniola Badmus
E gbo, taani igo rewa ju loju re? Se Toyin ni abi Muyiwa Ademola, abi Eniola nigo naa ye ju?
Read More »#Our5K ti da wahala sile lori ayelujara: Ile Igbimo Asofin ni wahala naa ti bere
#Our5K ti da wahala sile lori ayelujara: Ile Igbimo Asofin ni wahala naa ti bere Olayemi Olatilewa Lojo Wesde to koja yii nile igbimo asofin agba to kale siluu Abuja gbegi dina sisan owo egberun marun-un fun awon odo ile ...
Read More »Igbeyawo Asofin Moji Lawal niluu Eko leku!
Arabirin Moji Lawal, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ipinle Eko segbeyawo alarinrin lopin ose to koja yii pelu oko re, John Paul to je onisowo pataki. Arabirin Moji, eni to je obirin akoko ti o ma soju ekun ...
Read More »