L’ẹ́gbẹ́ òṣèlú APC; alága méjì lójijì lalẹ̀ hù—- Ajimobi àti Victor Giadom Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní bí ọ̀rọ̀ ńlá kò bá tí ì tán, èèyàn ńlá kò níí sinmi àròyé.Sinimọ́ oríta sì ń tẹ̀síwájú pẹ̀lú ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ ...
Read More »Blog Page
O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC
O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC Alaga patapata fun eto idibo ni orileede yii, Ojogbon Mahmood Yakubu lo n salaye yii ni ilu Abuja.O ni pelu rogbodiyan to n lo ni ipinle Edo, awon kan ti n ...
Read More »Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola
Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola Gomina tele ri ni ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ni o tinsalaye ni aimoye igba pe oun ko ni Ojogbon kankan pelu Asiwaju Bola Tinubu.O ni “ogede ko le wo ...
Read More »Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku
Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku Alhaji Atiku Abubakar ni igbakeji Aare tele ri ni orileede yii. Oun ni igbakeji Oloye Olusegun Obasanjo nigba naa.Atiku dije du ipo Aare ni odun 1993 ni eyi ...
Read More »Orisirisi: Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC
Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC Àjọ tó ń gbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà EFCC sọ pé àṣírí àwọn ayédèrú òṣìṣẹ́ ẹgbẹ̀rún kan àjọ tó ń ṣàkóso ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ nípìńlẹ̀ Kwara ti tú sí àwọn ...
Read More »Èèyàn 627 ló lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Naijiria ní Ọjọ́ Ẹtì
Èèyàn 627 ló lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Naijiria ní Ọjọ́ Ẹtì Ẹgbẹ̀ta lé lọ́gbọ̀n o dín mẹta èèyàn (627 )tuntun míì ló ṣẹ̀sẹ̀ lùgbàdi àrùn Kofi -19 ní Nàìjíríà. Àjọ tó ń rí sí ìdènà àti amójútó àjàkálẹ̀ àrùn apinni ...
Read More »Olu Jacobs sì wà láàyè
Olu Jacobs sì wà láàyè Agba oje ninu ere ori itage ni ede Oyinbo, Alagba Olu Jacobs ni awon iroyin eleje kan n gbee kiri lori ero ayelujara lati aaro oni pe, “olodi baba naa ti lo je ipe awon ...
Read More »Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩
Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩ Lati odun to koja ni ijoba apapo ti yi ojo isejoba awa-ara-wa kuro ni ojo kokandinlogbon osu karun-un odun si ojo kejila osu kefa odun. Eyi waye lati fi ...
Read More »O̩wó̩ pálábá 185 nínú o̩mo̩ e̩gbé̩ òkùnkùn ségí l’Eko
O̩wó̩ pálábá 185 nínú o̩mo̩ e̩gbé̩ òkùnkùn ségí l’EkoYínká Àlàbí Komisona olopaa ni ipinle Eko, Ogbeni Hakeem Odumosu tenu moo ipinle Eko ko ni faaye gba egbe okunkun rara. Eyi lo faa to fi tete pakiti mole lati gbogun ti ...
Read More »Ìdájọ́ ikú kò pọ̀jù fún gbogbo afipá bánilòpọ̀ – Ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn
Ìdájọ́ ikú kò pọ̀jù fún gbogbo afipá bánilòpọ̀ – Ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn Àgbáríjọpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọmọnìyàn bíi mẹ́rìnlà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ti korò ojú sí ìwà ìfipábánilòpọ̀ àti ìṣekúpani tí àwọn obìnrin ń kojú láwùjọ. Nínú ìpàdé àwọn oníròyìn tó wáyé lópin ...
Read More »