Gomina ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ti ranse ibanikedun si idile Hon Makinde Oladejo Samson to doloogbe lojo Aiku to koja yii, 27/12/15. Hon Makinde, omo egbe PDP, to je okan lara awon omo ile igbimo asofin ipinle Osun lo ...
Read More »Odun Iwude Ijesa: Gbogbo aye pejo saafin Owa Obokun
Ese ko gbero lojo Satide to koja yii niluu Ilesa nibi ti tonile talejo ti gbe pejo lati sodun Iwude Ijesa laafin Owa Obokun Adimula ti ile Ijesa, Oba Gabriel Adekunle Aromolaran. Gege bi a se gbo, ayeye odun Iwude ...
Read More »Odun 2016 yoo dun bi oyin: E ku odun tuntun
E ku odun tuntun. Odun ayo ati igbega ni yoo je fun gbogbo wa. Ase. Odun 2016 yoo dun bi oyin. Bee ni. E je ki eleyii je ero yin. Kosi tun maa jeyo ninu awon oro enu yin nigba ...
Read More »Ile itura alaja metalelogota (63) n jona bayii niluu Dubai
Bi a se n mura lati wo inu odun tuntun lo, ni aisun odun taa wayii, ile itura alaja metalelogota (63) kan an jona lo lowolowo bayii ni ilu Dubai eleyii ti won ko ti kapa ina naa. Bi a ...
Read More »Igbeyawo omo Adewale Ayuba fakiki
Idunnu obi ni ki omo o yan ko si yanju. Omo taa to, to si duro gbeko ni i pada di omo gidi lowo awon obi re. Eyi ni a le pe ni itan Tiwalade Ayuba lowo baba re. Ayo ...
Read More »Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko
Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ...
Read More »Oserebirin wo leyii, Se e damo bi??
E wo ohun ti enikan so nipa ile epo Bovas to wa niluu Ibadan
Awon arije ni madaru, ika, odaju, ole, wobia, wonbiliki le po ni Naijiria loooto, sugbon awon eniyan rere ko ti tan lawujo wa. Okan ninu won ni alase ile epo Bovas to kale silu Ibadan. Bakan naa ni awon eniyan ...
Read More »Ijamba oko niluu Eko lojo odun keresimesi
Ti e ba muti, e ma wako; ti e ba wako, e ma muti. Okunrin kan lo koja lo sorun lojo odun keresimesi to koja yii ni akoko ti gbogbo eniyan n yo ayo iwasaye Jesu olugbala araye. Ijamba oko ...
Read More »Owo ti te Jaguda, Mohammed Isah to lu komisanna olopaa meji ni jibiti
Sebi ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo awon olopaa ilu Eko ti te omo gambari onijibiti kan ti oruko re n je Mohammed Isah, to lu komisanna ipinle Ondo ati Anambra ni jibiti. Omokunrin onijibiti naa ...
Read More »