Home / Àṣà Oòduà (page 26)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Artist: Moyo Okediji​

My motherWho walks in the nightGraceful be thy stepsAs you place your heelOn the head Of a hidden Cobra And it cannot bite you.

Read More »

615″, ńọ́ń́bà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀

“615”, ńọ́ń́bà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Awọn agba bọ wọn ni oju bayii ni alakan fii sọri.Eyi naa lo mu gomina ipinlẹ Oyo,Ṣeyi Makinde gbe igbesẹ akin, ni bi o ṣe kede ńọ́ń́bà Ẹẹfa, ookan, ...

Read More »

Àrùn burúkú fé̩ tú Queens college

Arun iba buruku kan n da yanpon- yanrin sile bayii ni ile-ise awon obinrin (Queens college) to wa ni ilu Eko.Ironu ti dori awon agba kodo ni ipinle Eko bayii paapaa julo fun gbogbo awon to lomo nibe. Ile-iwe yii ...

Read More »

Ṣàgbẹ̀lójú yòyò, ni ọ̀pọ̀ àwọn òṣèré…. òjòpagogo

Ṣàgbẹ̀lójú yòyò, ni ọ̀pọ̀ àwọn òṣèré…. òjòpagogo Fẹ́mi Akínṣọlá Awọn agba bọ,wọn ni purọ n niyi,ẹwu ẹtẹ nii da bolowo ẹ lọrun lo mugbajugbaja agba ọjẹ oṣere Yoruba, Razak Ọlayiwọla ti gbogbo eeyan mọ si Ojopagogo bi o se sọrọ ...

Read More »

Ẹgbẹ ́Afẹ́nifẹ́re kọminú lórí ìwádìí ikú ọmọ Baba Faṣọranti to jẹ olori Afẹ́nifẹ́re – Odumakin

Ẹgbẹ ́Afẹ́nifẹ́re kọminú lórí ìwádìí ikú ọmọ Baba Faṣọranti to jẹ olori Afẹ́nifẹ́re – Odumakin Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí eyín bá n mì pẹkẹ pẹkẹ,erìgì ni kò fálẹ̀ mójúṣe rẹ̀.Ẹgbe Afenifẹre ti fi ero wọn han lori aijafafa ...

Read More »

E̩ tu èékánná lára S̩owore – Ilé-e̩jó̩

Ile-ejo giga to fi ikale si ilu Abuja lo pase fun ijoba apapo pe ki won yokun lorun Ogbeni Omoyele Sowore.Sowore ni o n gbimo lati se iwode Kan to maa mi ilu titi. Lati igba naa ni ijoba apapo ...

Read More »

Ọdún orò gbìnà yá, ìdájí ní àwọn olórò yóò fi máa yíde ìlú níṣẹ̀yin

Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn ...

Read More »

Bàbà wá Lérè paimo pé ọgọ́rin ọdún lónìí (80)

Ẹ jẹ ka jọ gbadura fun Ẹda Onile-ọla pe bi wọn ṣe ṣe tọdun yii ni wọn yoo ṣe tẹẹmi-in towo-tọmọ, ninu ilera pipe ati aiku ti i ṣe baalẹ ọrọ.

Read More »

Àmọ̀tẹkùn ni wọn yóó maa pe orúkọ ikọ̀ tó n pèsè ààbò yíká ilẹ̀ Yorùbá – Akeredolu

Àmọ̀tẹkùn ni wọn yóó maa pe orúkọ ikọ̀ tó n pèsè ààbò yíká ilẹ̀ Yorùbá…..Akerdolu Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe Yoruba bọ ,wọn ni Ogun ti yoo wọle koni,ọna la a tii pade ẹ lo bi ọrọ ti Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi ...

Read More »

Adúmáadán Àjèjé

Ẹmu daada ní ń bẹ nínú aháÒgùrọ̀ àtàtà ní ń bẹ nílẹ̀ akèrèǹgbèỌtí ò dá, àlejò ò lọ!Ẹni ọtí kìí tí AdúmáadánAdúmáadán Àjèjémá gbádùn ara rẹ lọ! ‘Òògùn ibà ni, òògùn ibà ni,’Bí eré, bí eré ìyálé ilé mútí yó!Ẹmu ...

Read More »