Òyìnbó kò mà le mú ojú kúrò lórò lára àwon omoge orílè èdè Nìjíríà rárá, nítorí won mò wípé arewà ni won, won sì mo ìké oko se, bí kò bá jé béè ogún-l’ógbòn àwon òyìnbó ni ó ti fé ...
Read More »Chimamanda Adichie se ayeye ojó-ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún mókànlélógójì (41) lóòní.
Chimamanda Ngozi Adichie ni won bí ní ojó keèdógún osù kesàn-án odún 1977 (15/09/1977), jé olùkòwé ní orílè èdè Nìjíríà, ó n ko ìtàn kékeré àti èyí tí ó pò, ó n ko èyí tí ó jé ìtàn ojú gbangban ...
Read More »Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó .
Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó . Ìyàwó tí ó rewà fé kí oko rè mo ohun tí ó n kó owó lé lórí, àti wípé ...
Read More »Owolabi Awodotun Aworeni omo Àràbà télè, Araba Adisa Aworeni, di Àràbà Àgbáyé.
Gbogbo onísèsi àgbáyé ti darapò láti fi Omo Ekùn je Àràbà káàkiri àgbáyé. Lóòótó òpò ni yóò ma rò wípé báwo ni ó se tún jé wípé omo Àràbà tí ó sísè náà ni ó tún jé, súgbón eni orí ...
Read More »Miracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán
Miracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán . Gbajúgbajà Bbnaija tí a mò sí Miracle tí ó lo fún ìsinmi olójó gbooro ti padà sí orílè èdè Nìjíríà gégé bí ó se kakè sí ...
Read More »Reekado Banks gba Larry Ekundayo l’álejò ní ilé rè.
Omo ikò ti egbé olórin ìgbàlódé tí a mò sí Mavin, Reekado Banks ti gba okùnrin a gba àmì èye ní àlejò ní ilé rè, àwon méjèjì pín fídíò náà sí orí èro ayélujára. E wo àwòrán won ní ìsàlè.
Read More »Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.
Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu. Arákùnrin kan ni a rí ní Ayobo, agbègbè kan ní ìpínlè Èkó tí ó n fi ìtò ara rè wè tí ó rò wípé omi ni látàrí ìmukúmu ...
Read More »Ayé Kareem ti yí padà di òtun láti ìgbà tí ó ti ya àwòrán Ààre Macron- Alákoso rè ló so béè.
Óríre míràn ti to omo kékeré, omo odún mókànlá tí a mò sí Kareem Waris Olamilekan tí olórun fún ní èbùn kí ó ma ta nkan, ó ti ya ààre ilè Faransé tí a mò sí Ààre Emmanuel Macron, nígbà ...
Read More »Ìròyìn Òrofó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
1 Ààrẹ Buhari yóò dé lónìí láti orílẹ̀ èdè China. 2 Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀ṣínbàjò gba àlejò àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọn gbé igbá orókè nínú ìdíje ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé. 3 Àwọn oníròyìn ń fi ìròyìn burúkú bá ìjọba Buhari ...
Read More »Arábìnrin kan ni ó bí ìbeta léyìn odún métàdínlógún tí ó tí se ìgbéyàwó.
Arábìnrin kan ni ó gbe lo sí orí èro ayélujára tí a mo sí facebook láti lo pín ìròyìn ayò wípé òhun bí ìbeta láti bí odún métàdínlógún sèyìn. Ó ko síbè wípé… ” èyin abiyamo mi ò le mú ...
Read More »