Home / Àṣà Oòduà (page 53)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

E wo nkan tí ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èkó tí a mò sí UNILAG se! Sé eléyìí kò ní jé kí àwon òdómobìnrin wa n’íìfé ohun afefe yèyè si báyìí.

   Nígbà míràn kò ye kí á bá àwon òdómobìnrin wa tí won n’íìfé ohun ayé wí jù, nígbà tí ó jé wípé àwon àwùjo wa kò kúkú mú orí eni tí n se isé takuntakun wú. Ká sisé kára ...

Read More »

Ifá náà ki bayi wípé: Adaku Adaoku

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi, aku ise ana o, a si tun ku imura toni, gegebi a se mo wípé oni je ojó isegun, ogun buburu yio se ninu igbesi ayé wa loni o Àse. E jeki a fi ...

Read More »

Oko àti ìyàwó se ayeye ojó ìbí won nígbà tí won pé ogóòrún (100) àti márùndínlógóòrún papò.

   Bàbá bàbá kan tí ó jé bàbá orílè èdè Nàìjíríà àti ìyá ìyá ni won se ayeye ojó ìbí fún nígbà tí won pé ogóòrún àti márùndínlógóòrún. Gégé bí olùsòrò kan lórí èro ayélujára se so àti olùsòrò gbogbogbò ...

Read More »

Àwon tí won ti yo kúrò àti àwon tí won lé ní BBNaija ti se àyéwò sí ilé-ìfowópamó tí a mò sí Heritage bank.

    Àwon Alábagbélé àti olùgbépò télè ti big brother Naija, àwon tí a mò sí Vandora, Princess, Dee one , Bitto àti àwon tí won lé kúrò Khloe àti k Brule se àbèwò sí ìkan lára àwon ilé-isé tí ...

Read More »

Òkan l’ára àwon anamoyayà (civil defence officer) ni àwon fúlàní darandaran pa ní ìpínlè Benue tí won sì sin ín pélú omijé.

Anamoyayà (civil defence officer) ni àwon Fulani darandaran pa ní ìjoba ìbílè Guma ní ìpìnlè Benue ni won ti sín pèlú òpòlopò omijé. Àwon emèwà rè ti sin ín tomijé tomijé.

Read More »

Arákùnrin kan tí ó jé ígbó àti arábìnrin òyìnbó yí se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.

Arákúnrin tí ó jé ígbò yí ti se ayeye ìgbéyàwó ìbílè alárinrin, tí ó sì ti fé ìyàwó rè òyìnbó n’ísu l’ókà. Gégé bí ìgbéyàwó náà se wáyé ní ojó ketàdínlógún osù kejì odún yí (17/2/2018) , a rí àwòrán ...

Read More »

E wo Nkan ti Obesere so Nipa Pasuma Ati Awon Osere Oni Fuji miran !

Read More »

Gó́mìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Akínwùnmí Àmbọ̀dé ju ọwọ́ lu òfin fún ìpamọ́ àti ìgbéga èdè Yorùbá

Aàrẹ Ọ̀nà Kakanfo, Ọ̀túnba Gàní Adams ti wọn ṣe ìwúyè fún ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, oṣù kini, ọjọ́ kẹtàlá ọdún Ẹgbàáléméjìdínlógún fi ẹ̀dùn ọkàn hàn nipa bi àṣà àti ìṣe Yoruba ti fẹ́ parẹ́.  Nigba ìwúyè, Ọ̀túnba Gàní Adams ṣe àlàyé ...

Read More »

Iwulo Ati Anfaani Ti Orí Nse Ninu Igbesi Ayé Omo Eda Eniyan

Ekaaro eyin eniyan mi, aku ise ana o, a sin tun ku imura toni, mose ni iwure laaro yi wipe Eledumare ninu aanu re koni jeki ire oni yi fiwa sile Àse. Idanileko mi toni da lori orí wa, opolopo ...

Read More »

Èsù Óólogbè!

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, bi a se njade lo loni Eledumare ninu aanu re yio jeki ire oni yi je tiwa Àse. Laaro yi mofe soro soki nipa èsù òdàrà, o seni laanu lode ...

Read More »