Home / Àṣà Oòduà (page 68)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Dangote fún àwon tí ó fi ara káásá níbi ìjàmbá iná ní ìlú Kano ní Mílíónú lóna èédégbéta náírà

Dangote fún àwon tí ó fi ara káásá níbi ìjàmbá iná tí ó selè ní ìlú Kano ní Mílíónú lóna èédégbéta náírà(#500,000,000)…

Read More »

Aisha El-Rufai se àgbékalè ètò abéré àjesára àti láti lé ìta lo l’ára omodé.

   Gégé bí Gómìnà ìpínlé Kaduna se pin, El Rufai. “Aisha El-Rufai ti se àgbékalè abéré àjesára àti ìpolongo láti lé ìta lo l’ára omodé.

Read More »

Stephanie Coker tún yo ní àrà òtò, ó tún yanilénu nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.

Stephanie Coker tún yo ní àrà òtò, ó tún yanilénu nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà. Stephanie Coker ti se ìgbéyàwó láìpé ojó, tí a bá ní p’aró ìgbéyàwó náà ye é…

Read More »

Àwòrán tí ó yanilénu tí Hailey Adeleke yà.

   Omobìnrin kejì ti gbajúgbajà olórin ní orílè èdè Nàijíríà , Davido , omo tí kò tíì fi esè kan ilè baba rè rí, ni ó ti n dàgbà sínú ewà , ó ti è ti rewà jù nínú àwòrán ...

Read More »

Ìyà tí òyìnbó fi je ìran Yorùbá kò kéré.

   Bí ó bá jé ti erú tí won kó wa ni kì bá da, bí kò se ikú burúkú tí won fi n pa àwon baba nlá wa. Béè won kò dá owó dúró. Kí Elédùmarè gbà wá lówó ...

Read More »

Àwòrán okùnrin kan ní orílè èdè Cameroon tí ó pa àwon omo rè méta.

   Yannick Arnauld Engolo láti orílè èdè Cameroon tí ó sì jé ènìyàn Swiss tí ó dá Miscas àti priceless corporation sílè ni a ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó pa àwon omo rè méta. Ó ti è pe ...

Read More »

Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíye ti kéde wípé àwon kò se mó.

Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíyè ti so wípé àwon kò se mó nígbà tí won se ìwóde gbangba ní ìpínlè Èkó.

Read More »

Mikel Obi fi àyè sílè bá àwon omo rè obìnrin méjì Ava àti Mia seré.

   Olga, ìyàwó ògbóntàrigì agbá bóòlù Mikel Obi, pín àwòrán ara rè nígbà tí ó n bá àwon omo rè seré , tí ó sì n ka ìwé fún won .

Read More »

Bukola Saraki pàdé Akòwé Ìjoba gbogbogbò tuntun Boss Mustapha.

  Ààre ilé-ìgbìmò asòfin Bukola Saraki pàdé Akòwé ìjoba gbogbogbò tuntun (SGF)Boss Mustapha.

Read More »

Ambode wo okò ojú omi láti rin ìrìn àjò lórí omi .

Dr. Akinwumi Ambode, Gómìnà ìpínlè Èkó se ayeye láti we okò ojú omi tí ó sèsè rà, okò ojú omi náà sì wà fún ìpínlè Èkó, bí ó se so wípé àwon n sisé láti jé kí ìrìnàjò orí omi ...

Read More »