Home / Àṣà Oòduà (page 81)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Tonto Dikeh Pèlú Muhammed Lai Nínú Okò Ojú Òfurunfú 

Gbajúgbajà òsèré Tonto Dikeh àti Asàkóso ìwí àti Àsà (minister of information and culture) Muhammed Lai. Ya àwòrán nínu okò ojú òfurunfú nínu ipò tí ó wà ní ìsàlè. “mo wo bí ayò mi se kún tó nígba tí Hon. ...

Read More »

Ewi Toni: Toju Iwa Re Ore Mi 

Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia, Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola. Okun l’ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ...

Read More »

Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní darandaran ní ìlú Edo 

NAN, Otaru ti ilè Auchi, Alhaji Aliru H. Momoh , ní ìlú Edo, ti kéde ní ojó ajé bí owó se te okòó lé mérin( 24) àwon afurasí Boko Haram tí won ń se bíi fúlàní darandaran ní agbègbè náà ...

Read More »

Laura Ikeji àti Ogbonaya Kanu kí omo tuntun sí  inú ìdílé won ní ìlú òyìnbó (u. S). 

 Omo ìyá Linda Ikeji , Laura Ikeji àti oko rè Ogbonna Kanu kí omo tuntun káàbò sí ìdílé won ní ìlú òyìnbó (U. S). Linda Ikeji kéde ewu omo tuntun náà lórí èro ayélujàra (instagram), níbi tí o  ti pín àwòrán ...

Read More »

Omo Oba Gwamnishu Harrison, tí won jígbé ,ké pé òun ń fi Nàìjíríà sílè 

 Olùdarí ilé-isé (CEO) ‘Behind Bar Initiative’, èyí tí ó pín àwòrán ara rè ní ibi tí ó gbé ń sunkún lórí èro ayélujàra (facebook). Ti so àsírí èròńgbà rè láti fi orílè èdè Nàìjíríà sílè lo sí ìlú òyìnbó (U. ...

Read More »

Èsì Ikú Tí Ó Pa Joy Odama Akékòó Odún Kejí (200l) Ti Ilé-èkó Gíga Ifáfitì Tí Ó Wà Ní Ìpínlè Cross River

Léyìn tí a gbó èsì ikú tí ó pa Joy Odama akékòó odún kejí (200l) ti ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó wà ní ìpínlè Cross river (university of science and technology (CRUTEC)) èyí tí ó kú ikú kàyééfi léyìn ìgbà ...

Read More »

Gbajúgbajà Olórin, Diamond Platnumz Ti Yanjú Aáwò Tí Ó Wà Láàrin Òhun Àti Ìyá Omo Rè

Gbajúgbajà olórin ní ìlà oorùn adúláwò tí a mò si Diamond platnumz ti yanjú aáwò tí ó wà láàrin òhun àti ìyá omo rè léyìn wákàtí tí ó bá a wí fún àìso òtító . Ó pín eré oníse amóhùn ...

Read More »

Odomokunrin Kan Ni Orile Ede Naijiria Ati Ara Binrin Oyinbo To Sanra Mu Ki Awon Eniyan Soro

Oro to panilerin ninu itakuroso ti o wa laarin arakunrin yi ati ololufe re tele eyi ti o yan je. Arakunrin naa kunle lati beere owo owo arabinrin orobo yi fun igbeyawo.. Eyi ni lati fi ife otito han si ...

Read More »

Sangbafo! Won Ge Apa Ati Ori Arakunrin Kan Nitori Ija Ile Ni Ipinle Delta

Ajalu ti o n sele lowo ni amai ati umuebu ni agbegbe iwo oorun ni ijoba ibile ndokwa ti owa ni ipinle delta – o ti gba ona iburu nipa pipa odomokunrin kan ti won ge apa ati ori re ...

Read More »

Aawọ ni Oshodi: Oluomo, Talonskibo, Harmburger Ati Oluwo.

        English Version Continue after the page break

Read More »