Home / Àṣà Oòduà / Tonto Dikeh Pèlú Muhammed Lai Nínú Okò Ojú Òfurunfú 

Tonto Dikeh Pèlú Muhammed Lai Nínú Okò Ojú Òfurunfú 

Gbajúgbajà òsèré Tonto Dikeh àti Asàkóso ìwí àti Àsà (minister of information and culture) Muhammed Lai. Ya àwòrán nínu okò ojú òfurunfú nínu ipò tí ó wà ní ìsàlè. “mo wo bí ayò mi se kún tó nígba tí Hon. Muhammed Lai sòrò kárakára nípa ìpìlè mi. Bí ènìyàn bá gbájú mó isé rè tí ó se olórun a ma fi èrè si. Inú mi ń dùn fún  ìgbésè tuntun…..

English Version
Continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*