Orisun iwe Iroyin: Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon eso oju ona ile Nigeria, Federal Road Safety Commission (FRSC), eka ti Ijebu Ode ti kede awon oju ona to lewu ni gbigba fun awon onimoto ni akoko poposinsin odun yii. Oju ...
Read More »Nipinle Ondo, awon osise ko rowo osu gba lati sodun Keresimeis
*Ijoba da awon osise 62 duro lenu ise Orisun: Olayemioniroyin.com Nibayii, Trade Union Congress (TUC) eka ti ipinle Ondo ti n ro gomina ipinle naa, Olusegun Mimiko, lati san awon owo osise ti won je seyin ati awon ajemonu won ...
Read More »Oselu Kogi: “Idi ti a ko fi yan Faleke ni yii” – Alaga APC
Alaga fun egbe oselu APC lapapo, Oloye John Odigie-Oyegun ti salaye idi pataki ti awon agba egbe naa fi pamopo lati yan Alhaji Yahaya Bello gege bi oludije ti yoo ropo Abubakar Audu, eni to jade laye saaju ki eto ...
Read More »“Ko saaye fun Toll-Gate bayii” – Egbe Akoroyin tiluu Eko
E gbe akoroyin, Nigeria Union of Journalists eka ti ilu Eko, ti gbe atejade kan jade eleyii to n ro ijoba apapo lati se atunse si awon oju ona masose wa ki won to ronu a ti da Toll Gate ...
Read More »GbajumoTV: Abiodun Majekodunmi (Baba Kekere)
What Is The Position of Ooni among Okanbi’s children? Is Ooni a King?
It is a well thought point that deserves commendation. Oduduwa begat Okanbi. Oduduwa is the first Ooni. Ooni is the shortend version of the appelation of Arole Oduduwa. Oonile is the owner of the land. He is also Oonirisa. He ...
Read More »Araga ni foto Yemi Alade yii
#Orisanla omoge onidodo
Read More »E wa wo ohun ti Ooni tun se nile ijosin
Ooni tuntun ti lo fori bale niwaju pastor fun esin awon alawo funfun, eyi to tunmosi jesu oga ogo nile ijosin. Awon kan ri gege bi ohun to ye fun eni to mo esin awon alawo funfun, sugbon awon kan ri gege ...
Read More »Ori kini won gbe sinu obe yii?
E woju obe ke e muyan. Iyan ‘re obe e re!
Read More »Ki lo gbayi bi aso ibile wa?
Aso to fi iwa omoluabi han to si rewa loju; aso to ponni le, aso tomo le jogun lowo eni. Ninu maaki mewaa (10), meloo le fe fun baba atomo re nipa imura won?
Read More »