Oni fila yii
Read More »Kini yoo sele si orekelewa aya Abubarka Audu?
Omodebirin yii ni okan ninu awon iyawo tuntun ti Abubarka Audu ko sile to fi n sararindin nigba aye re. Gege bi ohun ti Olayemi Oniroyin gbo, ojo ori omobirin naa ko le ju bi odun mejidinlogun (18) si ogun ...
Read More »Awon foto lati ibi eto isinku Abubarka Audu nipinle Kogi
Won sin Abubakar Audu lonii ni ilu re, Ogbonicha to wa ni ijoba ibile Ofu ni ipinle Kogi.
Read More »Ofin mokanla to le mu awo ara dabi omo tuntun jojolo
Orisun 1 E yee sa ara yin sinu oorun koja bo ti ye lo. Paapa julo, e sora fun awon oorun lati bi ago mewaa aaro si ago meji osan. Orisii oorun yii a maa mu ki awo eniyan o ...
Read More »“Iyawo mi n yale, o tun bimo ale fun mi”: Alabi yari ni kootu Ikorodu
Orisun Ogbeni Alabi Rasheed, eni odun mejidinlaadota (48) ti gbe iyawo re, Sherifat, lo si ile ejo lati tu yigi igbeyawo odun mewaa to wa laaarin won ka lOjobo ose to koja yii. Gege bi alaye Alabi ni Ikorodu ...
Read More »Baalu Aare Buhar ti bale niluu Iran
Aare Muhammadu Buhari ti bale ni Tehran to wa ni orileede Iran nibi ti yoo ti maa joko se ipade eleeketa iru e ti egbe awon orileede ti n gbe epo robi jade fun awon orileede agbaye.
Read More »Saraki gba Basketmouth lalejo niluu Abuja
Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, gba Basketmouth lalejo ninu ile re to wa niluu Abuja
Read More »“Ijoba APC gbodo je ki eto eko ofe rinle de ileewe giga” – Atiku
Igbakeji Aare ile Naijiria nigba kan ri, Alaaji Atiku Abubakar ti ro ijoba to wa lode yii, eleyii to wa lowo egbe oselu APC, lati je ki eto eko ofe ti won se ileri re kari gbogbo eka ikekoo patapata, ...
Read More »Simisola Omoayan: Omidan ti n filu dara
O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma kabamo leyin oro. Eni Edua Oke ba fe ni i fun ...
Read More »“Eyan Mayweather” ni awo orin tuntun Olamide Ogbeni (Mr) . Baddo
Olamide, Ogbeni (Mr) Baddo ti kede ojo ti yo ju awo orin re tuntun sigboro aye. Awo orin tuntun to pe akole re ni “Eyan Mayweather” ni yoo maa dagboro ru, bere lati ojo ketalelogun osu kokanla odun yii (23/11/15). ...
Read More »