Aje rere awole tọ ẹni kankan wa wáa….owo ayọ ni ama pajale ose..a oni pawo ẹjọ,wahala,isan,ibanuje .owo ayọ ni mapa…igi aje amaso nile oluka lukuwa…ase…ifakanso ni odu e bayi wipe…… Arakoko ki adifa fun wọn nilu ọwọlọ eyiti igi aje ...
Read More »Home / Iroyin Pajawiri (page 128)
Talo mo oruko, ogbontarigi okunrin ogun yi?
E jo kini oruko, ogbontarigi okunrin ogun yi?
Read More »E ku ojumo eyin omo ile kaaro ojiire. Se daada ni?
Mo gba l’adura wipe bi a tin jade lo fun ise oojo wa, ao ni ko el’esu l’ona. Iko ki n ko ejo l’ese, ayun lo ayun bo l’owo n yun enu. Atepe ni ese n te’na. Ire ila oorun, ...
Read More »Ogboni – Isese Lagba
IWURE ODUN TUNTUN 2015
IWURE ODUN TUNTUN A si ku odun, a ku iyedun. Olodun a wo omo fun wa. Kewekewe koni ko wa l’omo lo. Aseye ni alakan ns’epo ti e Aseye ni tiwa o. Aseti, akoti koni kan wa T’oko, t’aya ati ...
Read More »Aalo apamo – Mayaki Ojo
Aalo apamo Obi awe kan aje de oyo, baba kukuru de fila bentigo, kini nboba jeun ti kii mu sibi dani? Aguntan baba mi kan lailai, aguntan baba mi kan lailai, owoo ni nje kii je agbado. ( Ahon, oko, ...
Read More »Kini oma nda ija sileju laarin oko ati iyawo?
1, owo obe 2, ale yiyan 3, aigbora eniye (lack of understanding) 4, aini (poverty)
Read More »