Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojúLáti ọwọ́ Yínká Àlàbí Abajade ipade ile igbimo asoju to wa ni Abuja ni “a kuku joye san ju enu mi ko ka ilu lo”. Won ni ki gbogbo ...
Read More »Jonathan sàbẹ̀wò sí Buhari
Ara iroyin yajoyajo to wole ni abewo ti Aare ana, Omowe Goodluck Jonathan se si Aare Mohammadu Buhari ni Aso Villa to wa ni oluulu Naijiria ni Abuja. Ipade bonkele ni ipade yii nitori pe awon mejeeji tilekun mori ni, ...
Read More »Ìdíle Saraki àti ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara dájọ́ ìpàdé
Lẹ́yìn tí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara ti tẹ̀lé òfin tí wọ́n wo ohun ìní ìdílé Saraki èyí tí wọ́n ń pé ibẹ̀ ni Ilé Arúgbó ní ìlú Ilorin, ìpínlẹ̀ Kwara, gbogbo àwọn tọ́rọ̀ kan nínú rẹ̀ ti wá gbà láti yanjú aáwọ̀ láì ti ọwọ́ Ilé ẹjọ́ bọ̀ ọ́ mọ́.
Read More »Àwọn Yèyélórìṣà, Akirè Shrine Ilé Ifẹ̀, 2003.
Pitcture was taken by Prof. Moyo Okediji in 2003, he returned to find the group in 2015. But for the two women at the extreme left, all the others had transitioned.
Read More »Ilé-ẹjọ́ Tó Ga Jù Ní Samuel Ortom Náà Ló Tún Jáwé Olúborí Ní Benue
Ilé-ẹjọ́ tó ga jù ní Samuel Ortom náà ló tún jáwé olúborí ní BenueLáti ọwọ Yínká Àlàbí Iroyin yajoyajo to wole bayii lo n jeri sii bi ile ejo to ga ju lo to fi ikale si ilu Abuja se ...
Read More »Ìjọba Àpapọ̀ Kò Gbẹ́sẹ̀lẹ̀ Lé Owó Tó Tọ́ Sáwọn Ìjọba Ìbílẹ̀ L‘ọyọ
Lórí ọ̀rọ̀ kan tó gbà gboro kan pé àgbẹjọrò àgbà orilẹ̀-èdè Naijiria, Abubakar Malami ti pàṣẹ fún gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo láti gba àwọn alága káńṣù ti wọ́n yọ nípò pada, Ìjọba Ọyọ ti fèsì lórí ìṣẹ̀lẹ̀ náà.
Read More »Asiwaju Sí Aso̩ Lójú Eégún “Operation Àmò̩té̩kùn” Láti O̩wò̩ Yínká Àlàbí
Asiwaju Bola Ahmmed Tinubu to je asiwaju agba ninu egbe oselu APC ni gbogbo aye ti n wa kiri lati ojo ti Abubakar Malami ti ni idasile Amotekun ko ba ofin mu.
Read More »Ó ju ẹnu Malami lọ láti ní ètò náà kò bófin mu
Kí ojú má ríbi, gbogbo ara lòògùn rẹ̀, èyí ló mú kí Gómìnà ipinlẹ Ọyọ, Ṣèyí Mákindé sáré tètè gba ìlú Abẹokuta lọ, láti lọ ṣèpàdé pọ̀ pẹ̀lú Olóyè Olusẹgun Ọbasanjọ.
Read More »Ìdí tí nó̩ḿbà ìdánimò̩ kò fi jé̩ dandan mó̩ – Àjo̩ JAMB
Ẹ kò nílò nọńbà ìdánimọ̀ NIN fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020… Àjọ JAMB Fẹ́mi Akínṣọlá Ni báyìí Àjọ tó ń rí sí ìdánwò àṣewọlé ilé ẹ̀kọ́ gíga JAMB tí kó àfàró nípa lílo nọ́mbà ìdánimọ̀ “NIN” fún ìdánwò àṣewọlé ọdún ...
Read More »Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èsì àwọn ọmọ Nàìjíríà tó tẹ̀lé bí iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ṣe yin ara rẹ̀Lórí káàdì tí wọ́n fi síta lójú ...
Read More »