Two Ikò Boko Haram ti fi ojú winá ogun won sì ti bá ogún lo, tí ojú won sì rí méwàá ni ojó kejìlélógbòn osù kokànlá odún 2018 nígbà tí won tún fé se bí ìse won ní Arege ní ...
Read More »Arákùnrin tí ó n se yahoo ni ó ti ya wèrè nígbá tí bàbá eè kú tán ní ìlú Benin.
Kàyéfì nlá ni ó jé nígbà tí Arákùnrin kan ya wèrè ní ìlú Benin ní ìpínlè Edo. Gégé bí ìròyìn se so, òdókùnrin yí ni won fi èsùn kàn wípé isé kí á máa fi èro gbáni ni ó n ...
Read More »Mr Harri se ìgbéyawó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar ní ìpínlè Eko.
Arákùnrin kan ní orílè èdè Nìjíríà ti ya òpò èyan lénu látàrí sése ìgbéyàwó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar rè. Tí e bá rò wípé e ti ri tán , eléyìí tún ya ni lénu ò. ...
Read More »Olùsò àgùntàn tí a mò sí pásítò Adeboye tí ó jé olórí àwon omo léyìn Jésù ti ìjo RCCG fún àwon akékòó ìmò adajó tí ó yege jùlo mérin ní Fìlà orí ri awon adájó àti aso won.
Olórí àwon olùfokànsìn àti omo léyì jésù ti Ìjo àwon RCCG, gbogbo àgbáyé, Pásítò E.A Adeboye fún àwon akékòó tí won sèsè gboyè gégé bíi adájó mérin nínú ìjo rè ní àgbàlá HALL OF MERCY, Bwari ní ìpínlè Abuja, ní ...
Read More »Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29).
Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29). Gbajúgbajà arewà òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó n jé Lota Chukwu se ayeye odún mókàndínlógbon ojó ìbí ...
Read More »Arábìnrin omo odún méèdógbòn, tí ó tún jé a fi ewà s’oge, Chidimma Leilani Aaron ti gba àmì èye gégé bíi omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.
,Chidimma Leilani Aaron, omo odún méèdógbòn láti ìpínlè Enugu ti tayo àwon métàdínlógún (17) tí won jo díje fún omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà ti odún yí. O di eni kejìlélógójì tí yóò gba àmì èye yí ó sì ...
Read More »Tobi Bakre ya àwòrán pèlú Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka.
Ará ilé BBNaija télè tí ó sì jé àyànfé òpò ènìyàn tí a mò sí Tobi Bakre lo sì orí èro ayélujára rè tí ó n jé Insítágírámù láti pín àwòrán òhun àti àwon ènîyàn pàtàkì bíi Rita Dominic, Lolu, ...
Read More »Goodluck Ebele Jonathan se ayeye odún mókànlélógóta (61) ojó ìbí rè ní èní.
Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan GCFR GCON tí won bí ní ogún’jó osù Belu ní odún 1957, tí ó jé olósèlú ní orílè èdè Nìjíríà tí ó sì sin ìlú gégé bíi Ààre orílè èdè Nìjíríà láti odún 2010-2015. Kí ó ...
Read More »Kí ni ojú ò rírí, kárí ká f’ojú fò lópò. Njé Eléhà ninèyí tàbí Egúngún?.
Òrò náà só síni lénu ó tún buyò si, àbí bí èèyàn yóò bá jé òsákálá kí ó jé Òsákálá bí yóò sì jé Òsokolo kí ó ké Òsokolo, èwo ni òsákálásokolo. Èyí èèyàn sé Eléhà ni a ó pe ...
Read More »Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè.
Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè. Ògbólògbó adigunjalè ní òrò won ti já sí òfo látàrí àì jé kí àwon èèyàn ní ìfòkànbalè ní ìpínlè Delta. Àwon adigunjalè méjì tí ó n ...
Read More »