Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’EkitiYinka AlabiIdaji oni ojo kokanlelogun, osu kejila odun yii ni awon ara ilu Orin Ekiti dede de oko ti won ba Asia pupa to tumo si wi pe, ki awon ara agbegbe naa ma se ...
Read More »Kini a npe eleyi ni ede kaaro o ojire?
Èèmọ̀ rè é o !, Ìyàwó àfẹ́sọ́nà kú sínú Kànga, nígbeyàwó kọ̀la
Èèmọ̀ rè é o !, Ìyàwó àfẹ́sọ́nà kú sínú Kànga, nígbeyàwó kọ̀la Èèmọ̀ rè é o !, Ìyàwó àfẹ́sọ́nà kú sínú Kànga, nígbeyàwó kọ̀la Fẹ́mi Akínṣọlá À fi ká kún f’áàdúà kí ọjọ́ ayọ̀ ẹni ó má padà dọjọ́ ìbànújẹ́.Kí ...
Read More »Ìlé ẹjọ́ rọ Obalufẹ̀ ti Ilé Ifẹ̀ lóyè
Ìlé ẹjọ́ rọ Obalufẹ̀ ti Ilé Ifẹ̀ lóyè Ìlé ẹjọ́ rọ Obalufẹ̀ ti Ilé Ifẹ̀ lóyè Fẹ́mi Akínṣọlá Ó dà bí ẹni pé awuyewuye ìfinijoyè , ìyọnilóyè sì ń tẹ̀ẹ́wájú o , bí Ilé ẹjọ́ gíga ti ìpínlẹ Ọṣun ti ...
Read More »Ọ̀pọ̀ èèyàn ló sá fún mi nígbà tí mo dùbúlẹ̀ àìsàn…Taiwo Hassan
Ọ̀pọ̀ èèyàn ló sá fún mi nígbà tí mo dùbúlẹ̀ àìsàn…Taiwo Hassan Ọ̀pọ̀ èèyàn ló sá fún mi nígbà tí mo dùbúlẹ̀ àìsàn…Taiwo Hassan, Ògògó Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí ẹyìn ọ̀rọ̀ ò bá ì pọ́n, ẹnìkan kìí sí ...
Read More »Ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún, Ogogo.. ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ eré bọ́lùú wáyé
Ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún, Ogogo.. ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ eré bọ́lùú wáyé Fẹ́mi Akínṣọlá Ìlúmọ̀ọ́ká òṣèré tíátà Yoruba to tí ta gbòǹgbò káàkiri àgbáyé ni Alhaji Taiwo Hassan tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ sí Ogogo ọmọ kúlódò jẹ́. Nítorí náà kò ya ni lẹ́nu ...
Read More »Meet my Iyanifa!
Aboruboye meet my Iyanifa!
Read More »Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́
Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn òṣìṣẹ́ DSS gbé Soworẹ lásìkò tí ó fi ń léwájú ìwọ́de “Revolution now”.Ìtúsílẹ̀ rẹ̀ ń wáyé lẹ́yìn tí ó ti lo ọjọ́ márùndíláàdóje ní hàhámọ́ àwọn DSS. ...
Read More »Obi ni n bi arun
AboruAboyeAbosise..Ifa niiiiii Obi ni n bikuObi ni n bi arunObi ni n bi ofoObi ni n bi gbogbo ibi.Olodumare abawa fi obi biku, bi arun, bi ofo, bi gbogbo ajogun ibi aye wa o.Ase edumare. Sponsored by Asa Oodua Cola ...
Read More »Àsepò̩ tó dán mó̩rán wa láarin èmi ati àwo̩n èèyàn O̩yo̩ – Gómìnà
Èmi àti àwọn èèyàn Ọyọ yóò máa fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ológun.. Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé inú dídùn ń ni yoòbá níí mórííya àti pé yiinínú,níí jẹ́ kẹ́ni fẹ́ ṣèmìí. Bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ rí, bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo, ...
Read More »