Olórin orílè èdè Nàíjíríà, Emma Nyra ti gbìmò láti fi èbùn tí olórun fun han gbogbo àgbáyé lórí èro ayélujára ( Instagram). Olórin tí ó n lo ìsinmi rè lówó ní Dubai ti pín àwòrán tí ó yà ...
Read More »Peter okoye se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún mérìndínlógójì pèlú Omotola, Ebí àti òré.
Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr. P ti lé odún kan ní àná ó sì se ayeye ojó ìbí náà pèlú àwon ebí àti òré ní ilé rè. Gbajúgbajà òsèré, Omotola náà wà níbè.
Read More »Omobìnrin tí kò ti dàgbà púpò ni àwon olùdábòbò yin ìbon pa ní Agbonchia , ní ìpínlè Anambra .
Gégé bí èni tí ó pin sí orí èro ayélujára (Facebook) focuselema, àwon agbófinró ti jèbi pípa omobìnrin yí (tí àwon míràn ní okúnrin ni ) ti kú sí Agbonchia . A kò mo ohun tí ó fa ...
Read More »Kenneth Okonkwo àti omo rè yo ní àrà òtò.
Bí eni tí ó pin se so wípé . “Àwon òbí ní láti sóra fún àwon nkan tí won bá n se n’íwájú àwon omodé nítorí won n wò wá”.
Read More »Won dí afárá Niger nítorí ètò ìdìbò tí ó n lo lówó ní Anambra.
Afárá tí kò fi ìgbà kan dúró tí ni won ti tì látàrí ìdìbò tí ó n lo lówó ní Anambra.
Read More »Nabila Fash pe àwon obìnrin níjà bí won bá le ya àwòrán làì kunjú bí ti tò òun.
Bí Nabila, ìyàwó olórin kan, Oritsefemi se pín àwòrán tí kò ti kunju tí ó so wípé òun yà léyìn ìdárayá ní òwúrò àná.
Read More »Gómìnà Obina náà dìbò níbi ìdìbò Anambra.
Gómìnà Anambra Willie Obiano náà dìbò fún ara rè ní Otuocha ward 1 unit 004.
Read More »Àwon òdó ní Anambra pa màálù láti gbádùn ojó Nsala won nígbà tí won kò sì lo fún ètò ìdìbò.
Àwon òdó míràn gbádùn Nsala won, gégé bí won se pín sí orí èro ayélujára.
Read More »E ye àwon egbé ìyàwó Adesua Etomi wò.
Adesua ti se tán láti se tán láti se ìgbéyàwó. Ìgbéyàwó rè ti è ti súmón etílé.
Read More »Omo egbé PDP tí ó n lo fún ipò , Obaze ti lo dìbò fún ara rè.
Omo egbé PDP tí ó n lo fún fún ipò níbi ìdìbò Anambra Oseloka Obaze níbi tí ó ti dìbò fún ara rè.
Read More »