Home / Iroyin Pajawiri (page 78)

Iroyin Pajawiri

Akékòó Odún Keta (300l) Ti Oau Ti Eka Èkó ‘Pharmacy’ Rì Sómi, Tí Ó Sì Kú Sí Odò-ìwè (Swimming Pool) Ní Hòtéèlì. 

Akékòó odún keta (300l) ti eka èkó pharmacy, Obafemi Awolowo University; pàdánù èmí rè Lánàá léyìn ìgbà tí ó rì sómi nínú odò-ìwè (swimming pool) ní hòtéèlì tí a mò sí Hilton. A mò ó sí Fatile Emmanuel. Ìsèlè yí ...

Read More »

Owó Sìkún Àwon Olóòpá Te Arákùnrin Tí Ó Máa Ń Jí Okò Gbé Ní Yenegoa. 

Nígbà tí won ti mu fún èsùn kan náà. Arákùnrin tí ó wà nínú àwòrán ní ìsàlè yìí tí ó yan isé okò jíjígbé láàyò ni owó sìkún àwon olóòpá bà ní Yenegoa, ní ìjoba ìpínlè Bayelsa fún ìgbà keta. ...

Read More »

Oko Mi Máa Ń Fowósí Fóòmú Rè Wípé Òun Kò Tí Ní Ìyàwó ,erànmílówó.

 E jò ó Erànmílówó. Oko tí ó fémi sílé láti odún mérin séyìn, máa ń fowósí fóòmú rè wípé òun kò tí ní ìyàwó nígbà kúgbà tí ó bá ye kí ó so pé òhun ti láya. Yàtò sí ìyen ...

Read More »

Ìdí Tí Ó Fà Á Tí Mi Ò Ní Fi Lo Káàdì Ìrántí (Memory Card) Láyémi Mó. 

Ìdí méji pàtàkì tí mi ò fi lo káàdì ìrántí (SD card) mó. SD card tí a mò sí káàdì ìrántí (memory card) tí a tún mò sí káàdì ìrántí ìtá “external memory “,ní tòótó ó jé ohun tí ó ...

Read More »

Ní Iwájú Si : Nípa Ìlànà Oba Ifá Ti Gúúsù America (South America).

Àrídájú ti so wípé… 1. Àwon ènìyàn kan wà tí won ń lo orúko àti ipò Aláàfin láti fi lu àwon tí kò mò nípa Àsà yorùba ní jìbìtì ní ìlú òyìnbó. 2. Àwon babaláwo tí ó wà lábé ilé-ifá ...

Read More »

Fatai Owoseni sàkóso lílo bíbò ní Ikorodu láti owó omo oòduà rere !

Kàyééfi ńlá gbáà ni súnkere fàkere okò tí ó selè ní ìròlé àná ní bóòsì dúró Agric (Agric bus stop), Ikorodu ní ìlú Èkó. Tí ó kan ògá pátápátá ilé-isé olóòpá (commissioner of police) Ògbéni Fatai Owoseni láti yo òpòlopò ...

Read More »

Àwòrán Kí Ó Tó Di Ojó Ìgbeyàwó Láàrin Eléyàmeyà

Omo Ooduarere tún gbé tuntun dé ooo, àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó láàrin eléyàmeyà. Femi (yorùba) àti Mma rè tí ó ń jé OGECHI láti (River), inú won dùn púpò gan bí won se ya àwòrán papò nínu aso ...

Read More »

Iná gbé arabìnrin kan tí ó jé akékòó ifáfitì ní ìjoba ìpínlè River (River state university). 

Akékòó ifáfitì ní Ìjoba ìpínlè River kan tí a ò tíì mo eye to ó su ú ni Iná gbé ní ojó ìségun (Tuesday) ojó ketàlá osù kefà (June 13). A bá a tí ó subú lulè léègbé kan tí ...

Read More »

Ewi Toni: Toju Iwa Re Ore Mi 

Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia, Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola. Okun l’ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ...

Read More »

Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní darandaran ní ìlú Edo 

NAN, Otaru ti ilè Auchi, Alhaji Aliru H. Momoh , ní ìlú Edo, ti kéde ní ojó ajé bí owó se te okòó lé mérin( 24) àwon afurasí Boko Haram tí won ń se bíi fúlàní darandaran ní agbègbè náà ...

Read More »