Okunrin olokada kan ti won pe oruko re ni Ibrahim ni won sadeede ba oku re loju titi laaaro yii ni agbegbe Alaba Suru to wa loju ona masose Badagry niluu Eko. Igba ti won yoo ye okunrin naa wo, ...
Read More »Ile ise Ologun seleri owo tabua fun eni to ba ri Boko Haram
Olayemi Olatilewa Ile ise Ologun ile Naijiria ti se afihan foto awon ogbologbo alakatakiti esin Islam, Boko Haram bi ogorun (100) eleyii ti won on wa lati mu. Awon wonyii ni won se apejuwe won gege oloye agba ti ...
Read More »Photos: Meet the New Ooni Of Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Kabiyesi O)
ki Ade ko pe lori ki Bata pe lese o,Kabiyesi o.. Adeyeye Enitan Ogunwusi from the Geisi ruling house has been unveiled as the new Ooni of Ife. Moshood Adeoti, secretary to the Osun state government, confirmed this in an ...
Read More »Madueke ko ti bo ninu ejo, Ile ejo ko fun Saraki nisimi, Abba Moro tun ko sowo EFCC
Madueke o ti bo ninu ejo, Ile ejo o fun Saraki nisimi, Abba Moro tun ko sowo EFCC Olayemi Olatilewa Ile ise ti n risi iwa idaran niluu London, National Crime Agency [NCA] si n ba iwadii won lo ni ...
Read More »Ladoja setan lati gba ipo gomina pada lowo Ajimobi ni kootu
Ladoja ati Ajimobi: Taani ipo gomina yoo ja mo lowo ni kootu? Oniroyin: Olayemi Olatilewa Orisun Oniroyin: Twitter Nibayii, won ti kede ojo ti won yoo pari ejo, eleyii ti o je asekagba, to wa laaarin Senato Rasheed Adewolu Ladoja ...
Read More »Awon omo onimoto da gobe sile ni ipinle Ondo
Orisun Awon omo egbe onimoto NURTW eka ti ijoba ibile Owo to kale si ipinle Ondo buta sira won loju lojo Isegun to koja yii. Awon iko meji kan ti won je ti egbe NURTW la gbo wi pe won ...
Read More »Taiwo Osuolale (Ibeji Oran) naa ti ku o
Lose to koja ni iroyin nipa iku Taiwo Ibeji Oran fe si wa leti, e le ka iroyin naa ninu linki isale yii. www.olayemioniroyin.com/2015/10/ki-lo-sele-si-taiwo-leyin-iku-kehinde.html Iroyin naa ti fidi mule bayii. A si tun gbo wi pe won ti sin Taiwo ...
Read More »Ki lo sele si Taiwo leyin iku Kehinde Osuolale (Ibeji Oran)?
Leyin odun kan ti Kehinde Osuolale dagbere faye, iroyin mi-in tun ti kan wa wi pe ikeji re, Taiwo naa ti lo ba ikeji re lajule orun. Ohun ti a gbo ni wi pe ilu Abuja ni Taiwo ku si. ...
Read More »Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin.
Orisun Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin. Olayemi Olatilewa Awon olopaa ilu Ibadan ti bere si ni mu awon olokada ti won ba ti ko ju ero kan lo seyin ...
Read More »Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode
Orisun Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode *Komisanna lo pase fun awon olopaa Olayemi Olatilewa Owo awon olopaa ipinle Ogun ti te awon afura si kan gege bi omo egbe okunkun ni Ijebu-Ode. Gege bi atejade ...
Read More »