E MAA WI TELE MI : …….. *Oluwa gba eru iya lori mi. *Edumare ma se je ki n seru egbe. *Oluwa taari alaanu si mi. *Edumare fiso re so mi. *Oluwa pase irorun sinu aye mi. *Iku aitojo ko ...
Read More »Demo Blog With Map
Sun re o: Francis Aiyegbeni alase ‘D’Rovans Hotel’ ni ibadan
ojuluoooooooo! owe ni oro-aye, A NLO SI OYO O KOJU SI OYO A TUN BO LATI OYO OYO NAN LO TUN KOJU SI. SE BI ILU-GANGAN. iyen nipe ORUN LATI WA ORUN NAN LAO PADA SI. iku pa ABIRI o ...
Read More »Tani arakunrin-olokada yi jo ?
Kabiesi re Edua! a se otito ni oro awon agba to sope mejimeji ni Eledua da eniyan. OUN TO BA JO(resemble) OUN LA FI WE ARAWON EPO-EPA JO POSI ELIRI OWO-ALABAUN JO HANHAN-OPE. tani arakunrin-olokada yi jo(resemble)?
Read More »Ogulutu Oro Toni
Igbiyanju loma ngbeni de ipo ola Igbiyanju loma njeki kadara o se # wo Oremi masinmi igbiyanju oo ki o le dele ileri Majeki isoro kisoro kopa okanre da Lori ipinu ayo re Tepa mose re loni Ki osi mo ...
Read More »Iwure Owuro – 05.07.2016
E MAA WI TELE MI : …….. *Edumare ma se je ki n fi ota s’ore. *Oluwa gba mi lowo afoju-feni ma fokan-feni. *Edumare gbe mi leke abinu eni. *Oluwa ma se je ki n je egungun kehin eran. *Edumare ...
Read More »Ojumo Ire ni
Ile to mo wa loni, ka ma subu ka ma feyin owo danu,toripe ojumo ire ni, ka ma ko elenini ka ma ko agbako toripe ojumo ire ni,ori owo Lori wa loni, ESE aje lese wa lonj aji lowuro ati ...
Read More »Olojo ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa MONSURAT KEHINDE ADENEKAN ALANI ti won je okan pataki ninu ebi Omo Oodua Rere. Maami olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se ...
Read More »Eto Olobe Loloko Sokoyokoto Toni
Olorun ogo ni fun oruko re, oba to ni kokoro Iku ati iye lowo, oba ti o le pa, oba ti o le ji, adupe lowo eledua, oba ti o fi aanu re pawa mo. “FURAIDI IRESI” (fried rice) ni ...
Read More »Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile ...
Read More »Arun Karun Konifile Awa Se Ibugbe o
Eyin tiaa..akuu gbalegbata oni o…arun karun konifile awa se ibugbe o. Ase..Paronure lawaa..Se e gbagbe pe lati onilo di ola.faaji nson. Leyin Elere ti okan yin yan laayo. Pe kowa kolu siwa nibadi. Emaa gbagbe pe.idalu niselu. Onje tin lo ...
Read More »