Home / Demo Blog With Mappage 116

Demo Blog With Map

Owe Toni 27/03/2016

OWE TONI Bi o ti wu ki oju orun funfun to, sanma dudu yo wa ,,…………………,…………………………………………. No matter how bright the sky clouds will exist(challenges aren’t unusuall)

Read More »

Iwure Owuro 27/03/2016

:::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::: E MAA WI TELE MI : ……… *Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ogun aye koni bori mi. *Iji aye koni ja lu mi. *Inira ati idaamu, koni je temi. ...

Read More »

Ojopagogo lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Oruko wo won Npe Kini yi ni Ile Yin ?

?

Read More »

Opele ide (brass divination chain)

Opele ide (brass divination chain)

Read More »

Ti o ba ni #500, osi fe da ina okele, Bawo Ni wa Sena ?

TI O BA NI #500 KOSI KEROSINE KOSI GARRI TABI ELUBO OSI FE DA INA OKELE BAWO NI WA SE NA #500 fi se okele ‪#‎antyfolashadealawada‬

Read More »

Iwure Owuro 21/03/2016

E MAA WI TELE MI : …….. *Aye ko ni gbe ounje mi fun aja je. *Atije-atimu mi ko ni nira. *Oluwa so egan mi dogo. *Aye ko ni ta epo s’aso ala mi. *Fitila ogo mi ko ni ku. ...

Read More »

Ewi Toni – 20.03.2016

Ojumo ti mo Eda ti ji saye Eda ti ko mose asela Ka ji ni kutu hai Ka gbegba pota Iya Akanke nko O ti re werenjeje Baba Talabi da O ti sare re kutuwenji Ki ni n le wa? ...

Read More »

‪#‎Gbagede Asa-19/03/2016

Omo Oduduwa, Olodumare jogun awo to rewa fun wa; awo dudu ni gbogbo aye mo iran wa si, bo sie je wipe alawo pupa die naa nbe ninu-un wa. ……. Ewa n be lara awo dudu, nitori awa gan ni ...

Read More »

Ewi Toni: Atoto arere

Gbogbo omo Yoruba Ki gbogbo eye igbo pa lolo Etu to n numo lowo O ma lee numo Gbogbo Ekulu ko ma lee numo loka Omo Ade ti de to fe korin ogbon Akewi Imoran de to fe farofo sasaro ...

Read More »