Igbakeji Aare ile Naijiria nigba kan ri, Alaaji Atiku Abubakar ti ro ijoba to wa lode yii, eleyii to wa lowo egbe oselu APC, lati je ki eto eko ofe ti won se ileri re kari gbogbo eka ikekoo patapata, ...
Read More »Demo Blog With Map
Won gun pasito ijo RCCG lobe niluu Ota
Edward Campbell, eni odun mokandinlaadota (49) ni won ti gbe lo si ile ejo lojo Eti to koja yii pelu esun wi pe o gun pasito Redeemed Christian Church of God (RCCG), Dotun Olojede, lo be. Ile ejo Majisireeti to ...
Read More »Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan
Awon Yoruba bo, won ni iku ti o ba pani, toba si fila eni lo ope ni ka maa du. Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan l’Ojobo ose to koja yii nigba ti maalu awon ...
Read More »Simisola Omoayan: Omidan ti n filu dara
O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma kabamo leyin oro. Eni Edua Oke ba fe ni i fun ...
Read More »Otun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye
Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye leni odun metadinlaadorun (87). Oloye yii la gbo wi pe o dake ninu ile re to wa ni agbegbe Ikolaba ...
Read More »Abule wo ni sisi yii ti wa na?
Eleyii tun gaju!
Read More »E wo ohun ti won fi ibeji da lara
Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji ...
Read More »Inu fiimu wo ni aworan yii ti jade?
Yeepa! Mercy Aigbe di Sulia Ayetoro
Sulia kan, Mercy kan, Walahai Ayetoro kan ni
Read More »Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin
Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun ju lo. Ti eni naa yoo si bo ninu wahala ...
Read More »