Home / Àṣà Oòduà / Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle

Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle

Titi di akoko yii, enikeni ko le so pato ohun to sekupa oludije ipo gomina labe egbe oselu APC ni ipinle Kogi, Abubakar Audu. Se ise aye ni abi amuwa Olorun oba? Ohun ti ko ye enikan, kedere ni niwaju Olorun Oba. Olayemi Oniroyin, joojumo ni mo n kogbon aye. Gbogbo igba ni mo si n ran ara mi leti wi pe asan ni duniyan, omulemofo nigbogbo re pata je. Sugbon adura kan lo wu mi ti mo fe se fun gbogbo eyin ololufe Olayemi Oniroyin, ojo ti ire ayo yin ba wole de, imo esu ko ni ba ayo naa je. Odun n lo sopin, ibanuje, o kere, o tobi, ko ni wo ile wa. A ko ni rogun ekun, idaamu, wahala, ipayinkeke ko ni yale enikeni wa. Amin.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ojo keji

Ó San Owó Ilé Ìwé Mi Títí Mo Fi Jáde, Ṣùgbọ́n Mo Fi Májèlé San!

Àti ilé ìwé e gírámà ni èmi àti Kọ́lá ti jọ ń fẹ́ ra wa. Àwọn òbí i mi ò kí ń fẹ́ rí Kọ́lá pẹ̀lú u mi nítorí ààfín ni. Nígbà tí mo fẹ́ wo ile ìwé gíga ni bàbá à mi ní àìsàn an rọ́pá, rọsẹ̀,ọpẹ́lọpẹ́ kọ́lá tó san owó ilé ìwé è mi láti ìgbà tí mo wolé ẹ̀kọ́ gíga títí mo fi jádé. Nígbà ti mo lọ ṣe agùnbánirọ̀ mo pàdé sẹ́nátọ kán,èmi àti ẹ̀ sì ...