Se Ruggedman ba iyawo 9ice sun looto? *Adigun Alapomeji ti pada soro *Asiri ikoko ti de gbangba Olayemi Olatilewa 9ice ati Toni Alexander Abolore Ajifolajifaola eni ti gbogbo eniyan mo si 9ice ti ni oun ko ni darijin ore oun ...
Read More »Demo Blog With Map
Awon omo onimoto da gobe sile ni ipinle Ondo
Orisun Awon omo egbe onimoto NURTW eka ti ijoba ibile Owo to kale si ipinle Ondo buta sira won loju lojo Isegun to koja yii. Awon iko meji kan ti won je ti egbe NURTW la gbo wi pe won ...
Read More »Nje ohun to buru wa ninu ara bibo?
Nje ohun to buru wa ninu ara bibo? Idahun awon eniyan wa ninu linki isale yii: https://www.facebook.com/photo.php?fbid=904657846286766&set=gm.1070531176331524&type=3
Read More »Taiwo Osuolale (Ibeji Oran) naa ti ku o
Lose to koja ni iroyin nipa iku Taiwo Ibeji Oran fe si wa leti, e le ka iroyin naa ninu linki isale yii. www.olayemioniroyin.com/2015/10/ki-lo-sele-si-taiwo-leyin-iku-kehinde.html Iroyin naa ti fidi mule bayii. A si tun gbo wi pe won ti sin Taiwo ...
Read More »Awon omo Iraq n fi obe ge ori ara won nibi won ti n gbadura
Awon omo orileede Iraq ti won sin orisii esin musulumi kan ti n je “Shia Islam” n fi obe ge awo ori ara won nibi won ti n gbadura.
Read More »Onka ede Yoruba 100 – 20,000
Orisun Onka ede Yoruba 100-Ọgọrun 110- Adọfa, àádọ́fà 120- Ọgọfa 130- Aadoje 140- Ogoje 150- Adọjọ, àádọ́jọ 160-Ọgọjọ 170-Adọsan, àádọ́sán 180- Ọgọsan 190-Mẹwadinigba 200-Igba E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow)
Read More »E wo ohun ti Funke Akindele n se lowo?
Funke Akindele ti pada si ni sere idaraya eleyii to n se lati din ara sisan re ku. Awon obirin onise tiata maa n se eleyii lati mu ara awon wa ni ipo odo, eleyii to se pataki si irufe ...
Read More »Aye ye Rotimi Amaechi ninu Abuja
Aimoye ero wa pade Rotimi Ameachi nikete to jade ninu ile igbimo asofin Abuja lonii. Foto Rotimi Amaechi ati iyawo re leyin to yege niwaju ile igbimo asofin agba gege bi minisita ti won yan
Read More »E wa wo bobo to fi tattoo ya Davido si aya re
Davido pada pade bobo to fi tattoo ya aworan omo baba olowo si igbaaya re. Ebun ti Davido fun naa ni alakorun ti won fi goolu se. O si so fun bobo naa wi pe awon ti di abi kan ...
Read More »[Foto] Aso oge Toyin Aimakhu le ku! #Igo loju omo odaran
#ToyinAimakhu Se igo yii o wa poju?
Read More »