Home / Demo Blog With Mappage 156

Demo Blog With Map

Oko Ofurufu Helicopter Ti Awon Omo Ologun Ti Jalule Ni Ilu Kaduna

Oko ofurufu helicopter eleyii ti awon ologun n lo fun idanileko lo jabo ni ibuba awon omo ologun to wa ni Kaduna leyin iseju mewaa to gbera soke. Ilu Abuja lagbo wi pe oko ofurufu naa n lo ki lala ...

Read More »

Osise Arik Airline Ba Naija Loju Je Niluu London: Won Ka “Lafun Funfun Alata’ Mo o Lowo

Owo ti te CHIKA EGWU UDENSI, okan ninu awon osise ile ise oko ofurufu ARIK Airline ni papako ofurufu HEATHROW ti ilu London pelu ogun oloro kokeeni. Ogun oloro ti won ka mo bobo naa lowo ni won ni iye ...

Read More »

“Oserekurin Ti Mo Fe Lati Je Ete Re Ni…”: Tani Okunrin Ti Bimbo Thomas Feran Lati Kiisi?

Ti a ba n so nipa ise tiata ile Naijeria, Bimbo Thomas ti kuro ni ojewewe ti won nawo juwe re. Lara awon fiimu to ti kopa ribiribi ni eleyii ti Funke Akindele gbe jade ti won pe akole re ...

Read More »

Milionu Mefa Ti Gbe Omo Naijeria Wonu Ese-Mefa: Ojukokoro Ti Pa Chukwudi!

Chukwudi, omo odun mejidinlogbon (28)ti padanu emi re leyin igba to ta kidinrin re ni milionu mefa owo naira (N6million)niluu Malaysia Chukwudi la gbo wi pe o tirafu lati ilu re, Owerri, ipinle Imo lati lo siluu Malaysia nibi to ...

Read More »

Iyalenu: Foto Ohun To N Sele Ni Ibudo Awon Ti B’Haram So Di Alailara, Alaini Nnkankan Niyii

Ibudo awon eniyan ti Boko Haram So di alailara ati alainile lori latari ijamba ati ikolu Boko Haram ni yii ni Maiduguri to wa ni Ipinle Borno. E le biliifu wi pe sobiri ti won fi n re ile ni ...

Read More »

Abiyamo Fi Omije Gbe Omo Re Sinu Koto

Ipokipo ti eda ba wa laye, e pe ko maa dupe. Ibikibi ti ori ba da ni si ka fi ope fun Oluwa oba nitori awon kan ko tile ni ida kan ninu ogorun anfaani ti a ni.  Ebi n ...

Read More »

Won Fi Leta Pe Pasuma Pe Ko Wa Korin Ni Soosi Baba G.O Adegboye

Abi foto Buroda Alabi Pasuma ko ni mo n wo yii ni? Ko ma si eni ti Olorun ko le fi owo to lokan sa o. Burudo Pasuma, Orobokibo Creator, Oga Nla 1, Ijaya of Fuji, Oluwa yoo ma so ...

Read More »

Sayewo Omo Ita, Jaguda Ti Buhari Fi Se Oludamora Nipa Oro To N Lo Nile Igbimo Asofin

Honorebu Suleiman A. Kawu ni yii, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ti n fo iganna nigba rogbodiyan to waye nile igbimo asofin ni akoko ti Goodluck Jonathan wa lori oye gege bi Aare ile Nigeria olominira. Maanu yii ...

Read More »

Oko Toyin Aimakhu, Adeniyi Johnson Ti Dale Ife

Laipe yii ni omobirin naa yo oruko oko re kuro ninu oruko re. Bakan naa ni awon eniyan tun kiyesi wi pe awon foto oko re to wa lori ikanni instagram re lo ti fe e gbonyo tan. Adeniyi Johnson ...

Read More »

“Kini Idi Ti Fasola Fi Wu Ewu Funfun Lori Ko To Kuro Nijoba?” Ninu Iwe Iroyin Owuro Ni Idahun Naa Wa

Akole gbagada to jade lati inu iwe Iroyin Owuro ti ose yii lo n so nipa ohun to faa ti Fasola fi wu ewu lori ko to pari ijoba re nigba ti awon akegbe re bi Mimiko ati Ajimobi n ...

Read More »