Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn ...
Read More »Demo Blog With Map
Bàbà wá Lérè paimo pé ọgọ́rin ọdún lónìí (80)
Ẹ jẹ ka jọ gbadura fun Ẹda Onile-ọla pe bi wọn ṣe ṣe tọdun yii ni wọn yoo ṣe tẹẹmi-in towo-tọmọ, ninu ilera pipe ati aiku ti i ṣe baalẹ ọrọ.
Read More »Àmọ̀tẹkùn ni wọn yóó maa pe orúkọ ikọ̀ tó n pèsè ààbò yíká ilẹ̀ Yorùbá – Akeredolu
Àmọ̀tẹkùn ni wọn yóó maa pe orúkọ ikọ̀ tó n pèsè ààbò yíká ilẹ̀ Yorùbá…..Akerdolu Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe Yoruba bọ ,wọn ni Ogun ti yoo wọle koni,ọna la a tii pade ẹ lo bi ọrọ ti Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi ...
Read More »Adúmáadán Àjèjé
Ẹmu daada ní ń bẹ nínú aháÒgùrọ̀ àtàtà ní ń bẹ nílẹ̀ akèrèǹgbèỌtí ò dá, àlejò ò lọ!Ẹni ọtí kìí tí AdúmáadánAdúmáadán Àjèjémá gbádùn ara rẹ lọ! ‘Òògùn ibà ni, òògùn ibà ni,’Bí eré, bí eré ìyálé ilé mútí yó!Ẹmu ...
Read More »Odù Ifá Mímọ́ Ọ̀bàrà Bubu
Ekáàrọ̀ọ́ ẹ̀yin ènìyàn mi, aojiire bi? Oni a sanwa o, ao rí tiwa se loni, gẹ́gẹ́bí òní ṣe jẹ ọjọ́ àíkú, gbogbo wa koni kánjú ku lágbára Olodùmarè àṣẹ.E jékí a fi odù ifá mímọ́ ọ̀bàrà bubu yi ṣe ìwúre ...
Read More »Fayose kò mo̩ bò̩ò̩lì àti àgbàdo je̩ tó mi,àmó̩… – Fayemi
Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re.Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to wa laarin oun ati gomina ...
Read More »Ti o ba ka iwe yii fi ara e han
Gege bi Omo Oodua Rere, Nje E Mo Oruko ti won pe kokoro yi ?
Kini Oruko ti won pe kokoro ti o wa ninu aworan oke yii ?
Read More »Awa Omo Oudua Rere: E Da Epa Owe Kan To Ba Oro Aja Lo
Owe Yoruba
Read More »