Home / Demo Blog With Mappage 29

Demo Blog With Map

E ba mi Pari owe yii

Read More »

E fun mi ni owe to ni Ile(house) ninu ?

Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu. E seun.

Read More »

Owonrisogbe – Ifá Naa Ki Bayi Wipe: Biijo biijo…

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku orire osu Ògún tuntun to bawa layo ati alaafia, osu naa yio sanwa sowo, somo, sile kiko, moto rira, ire oko/aya ati aiku baale oro yio ...

Read More »

Iya mi Osun Sengese

Iya mi Osun Sengese Ladekoju Ebora ti n gbenu omiLagbolodo,Iwo ni mo nkee si o.Osun ma n bo oYago lona o.

Read More »

Eríwo Yà! Eríwo Yà!! Eríwo Yà!!!

Ṣí Gbogbo Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀, Ní òní yìí (ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, oṣù kejèe 2019) ni ìgbẹ́jọ́ tó bẹ̀rẹ̀ ní ìtàdògún tó kọjá lọ (Tuesday, 9th of July 2019) parí (tí ìdájọ́ sì wáyé pẹ̀lú) lórí ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ...

Read More »

Má Jẹ Àkàrà Ọ̀ràn Sími Lọ́rùn

Aruku madẹgbẹ má jẹ àkàrà ọ̀ràn sími lọ́rùnAruku madẹgbẹ Mo sé ní ìwúre fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní òwúrọ̀ tòní wípé àlejò ọ̀ràn tó ma kóbá èmi àti ẹ̀yin kò ní bá wa ní àlejò ooo

Read More »

Ìwúre Toni

Ikú tó yọ lóòré ńkọ́ Àrùn tó yọ lóòré ńkọ́ Ẹjọ́ tó yọ lóòré ńkọ́ Òfò tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí kọ̀wun, àyà mí kọ̀wunMoti jẹ kọ̀ǹkọ̀ mo ti kọ̀ Owó,aya, ọmọ,gbogbo ire tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí gbàwun, àyà mí gbàwunMoti jẹ ...

Read More »

O lápátí

Kò tirẹ̀ lápátíKò sí ẹni lè gbà pe kí wọ́n dojú ìbọn kọ òwun Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun ti a wọ inú rẹ̀ yí wípé ògún lákayé kò ní dojú ìjà kọ èmi àti ẹ̀yin tọmọ tọmọ ...

Read More »

E ku Ose Ifa

Aráká-AjagaAràkà-AjagaAdifun Eniyan Ti Mú Iyè Meji Sin ÈdúÈnìyàn Ti O Sin Èdú,Ko Ma Se Iyè MejiAráká-Oku-AjagaAràkà-Oku-Ajaga ??Ase Tedumare?? ?Ifabukky Care?

Read More »

Ìgbín

Àkòrò ní ìgbín fà gungi Ìgbín kò lọ́wọ́ Ìgbín kò lẹ́ṣẹ̀ Àkòrò ní ìgbín fà gungi Mo sé ní ìwúre fún èmi àti ẹ̀yin ní ojúmọ́ tòní wípé Olódùmarè yoo tì wá lẹ́yìn, ìgbìnyànjú wa láti gun òkè ọlà, kò ní já sófo

Read More »