Àkúsàba Àyàndà Awo ilé Olúmẹ̀ri Àápáálá Ọmọ ilé san wón ó joko lọ Níjọ́ tí ń ṣọ̀gbọ̀gbọ̀ àrùn Tí ń najú aláì le dìde Olúmẹ̀ri Àápáálá làrùn ń ṣe Òún wá á le gbádùn gbogbo nǹkan òun lójú ayé òun ...
Read More »Demo Blog With Map
Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè.
Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè. Alex Asogwa pín àwòrán rè tí ó rewà àti ti ìyá rè àti ìyá ìyá rè tí ó rewà, ìran méta tí ó rewà ...
Read More »Omokùnrin odún métàlá (13) ni àwon olópàá ti mú látàrí ìbèrú tí ó ní sí won.
Omokúnrin kékeré kan ní won ti mó’ lé ní àgó olópàá látàrí ìbèrù tí ó ní fún àwon olópàá. Gégé bí ìròyìn se so, omokùnrin odún métàlá, tí ó sí jé olórí okúnrin ilé-èkó won, ni ó n pon omi ...
Read More »Tiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter
Obìnrin àkókó ní inú egbé Marvin kúnlè wò ní orí ìkúnlè nígbà tí ó kí ògà gun àti ògbóntàgirigì tí a mò sí Shina Peter nígbà tí won n sí ilé-isé pefume brand, Sappire Scent ní Lenox mall ní ìpínlè ...
Read More »Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.
Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná. Ààre ilé ìgbìmò Asòfin tí a mò sí Dókítà Abubakar Bukola Saraki ní àná tí lo kí omo egbé oní àbùradà tí a mò sí egbé PDP, èyí tí ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di onó ìgbéyàwó ti olópàá kan àti olùwòsàn.
Gégé se gégé, onígègè tó pàdé asòpá ni òr olópàá àti olùwòsàn yí jé, bí olópàá bá kojú dogun tí ó sì pa lára, olùwòsàn tí ó jé ìyàwó rè yóò sì ba wò ó sàn . Àwòrán ti aya ...
Read More »Ọmùtí Gbàgbé Ìṣẹ́ (Ìrònú Ọlọtí)
Ilé ọlọ́ti ni ilé ìtura, ibẹ̀ ni àwọn ọ̀rẹ́ ti npàdé fàájì Ibẹ̀ náà ni àwọn èké, àti ọ̀dàlẹ̀ tin pàdé ara wọn Ti ọti bá wọra tán, ara a sì rọ̀ wọ́n pẹ̀sẹ̀, Ìgbéraga á wá wọ̀ wọ́n lẹ́wù ...
Read More »Ìpínlè Osun, Ìpínlè Omolúàbí yóò yan ìpín won lónìí, ojó Àbáméta nígbà tí won yóò dìbò fún eni tí won fé gégé bí gómìnà Omolúàbí.
Gégé bí a ti mò wípé òní tí ó jé Ojó Àbáméta ni ìpínlè Osun yóò dìbó fún ènìyàn tí won fé kí ó di aláse lórí won. Egbé kòòkan sì ti fi omo egbé sílè . Gboyega Oyetola ni ...
Read More »Gómìnà Arégbésolá fún àwon olùkó ní èbùn okò àti àwon èbùn míràn.
Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Rauf Aregbesola lo sí àjo àwon ilé-èkó àwon alákóbèrè pèlú àwon adarí míràn tí won péjú sìbè láti pín okò fún àwon òsìsé. Kìí se okò níkan ni ó fún won o bí ...
Read More »Àwon arákúnrin méjì kan jà lórí eni tí yóò jókòó sí iwájú okò.
Àwon èrò méjì ni a rí lónìí tí won n jà látàrí eni tí yóò jóko sí iwájú oko ní Èkó . Nígbà tí ó yá ni awakò ti awon méjèèjì jábó látàrí bí won se n se bí eni ...
Read More »