Gbajúgbajà tí olórun fún ní èbùn tí ó bùáyà, tí a mò sí òòsà obìnrin ti ilè Roman lo sí ibi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Oritsefemi àti Nabila Fash pèlú àyà rìwòwò tí olórun fún lo sí ibi ayeye ...
Read More »Oritsefemi ná owó fún ìyàwó rè , Nabila Fash níbi ìgbéyàwó ìbílè rè.
Oritsefemi ná owó fún ìyàwó rè , Nabila Fash níbi ìgbéyàwó ìbílè rè. Oritsefemi àti ìyàwó rè, Nabila Fash ti se ìgbéyàwó ní ilú èkó, e tún wo àwòrán Àkàrà òyìnbó won (Cake) tí tokotayà sì n wo ojú ara ...
Read More »Àwòrán Oritsefemi àti Nabila Fash léyìn tí won se ìgbéyàwó ìbílè ní òwúrò tán kí ó tó di wípé won se ti alárédè.
Àwòrán Oritsefemi àti Nabila Fash léyìn tí won se ìgbéyàwó ìbílè ní òwúrò tán kí ó tó di wípé won se ti alárédè. Oritsefemi àti ìyàwó rè tí tè síwájú fún ìgbéyàwó alárédè . E wo Nabila Fash bí ó ...
Read More »Banky W lórí ìkúnlè ní iwájú awon emèwà rè nígbà tí won ro òjò àdúrà fun.
Banky W lórí ìkúnlè ní iwájú awon emèwà rè nígbà tí won ro òjò àdúrà fun.Àwòrán rí ó rewà níbi tí àwon egbé oko (Banky W) ti n se àdúrá fún òré won tí ó n lo sí ìgbé ayé ...
Read More »Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò darapò mó egbé APC.
Olóyè Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò fi egbé alásìá, PDP (People Democratic Party)sílè lo dí egbé onígbálè APC (All Progressive Congress). Ìròyìn jé kí á mò wípé ìgbésè Obanikoro lo sí egbé tuntun ti bèrè láti bi osù mélòó séyìn ...
Read More »Ebuka Obi-Uchenda àti ìyàwó rè, Cynthia Obianodo níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti Adesua Etomi.
Ojó tí a ti n retí ti pé o! Ebuka pín àwòrán aso tí wò lo sí #BAAD2017 tí ó túmò sí Banky Adesua 2017. Níbi tí ó ti fi ara rè hàn. E wo bí gbajúgbajà yí ...
Read More »Arábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.
Odóbìnrin kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Bosslady ni orúko rè n jé ní orí èro ayélujára (Instagram) ti jé kí ó di mímò wípé òun n gba ààwè funfun fún Wizkid, nítorí bí ó se so ó ní Wizkid ní ...
Read More »Èmi ni mo ko àkosílè orin tí Davido sèsè ko tí ó n jé “like that” Teni tí ó jé adá ni lára yá , Teniola Apata.
Olórin kan ní orílè èdè Nàìjíríà adá ni lára yá Teni ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi hàn wípé òun ni òun ko àkosílè Orin tí gbajúgbajà olórin Davido sèsè ko, ó ní òun ni òun ...
Read More »Jude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí Aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè.
Ó ti dá àwon olólùfé won lóhùn lórí èro ayélujára (Instagram), Jude Okoye ti fi ogbón sòrò nípa aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè tí ó sí wípé òun kó ni olórí ebí won. Ó ko síbè wípé. ...
Read More »Okò tí ó gbé epo petiírólù àti okò èrò ni ó kolu ara won ní Orlu Imo, ogbòn èèyàn ni ó kú.
Ìjàmbá nlá ni ó selè ní orí afárá (bridge) tí ó gbajúgbajà ní Njaba lónà Umuaka – Okwudor ní ìpínlè Imo. Gégé bí ìròyìn se so okò epo petiírólù àti ti gáàsì tí ó kolu bóòsì elérò méjìdínlógún ní Orlu, ...
Read More »