Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 46)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Kinin Oruko Ara Kunrin Yi ?????

(gbajugbaja osere oni theatre )

Read More »

Ohun méje tí ó jé èdùn okàn tí won kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga ifáfitì.

Ohun méje (7) tí ó jé èdùn okàn tí enikéni kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga. 1- ilé-èkó gíga ifáfitì wà fún mímo irú èèyàn tí o jé, lo àkókò àti ànfààní tí o bá ní ...

Read More »

Àwon agbésùmòmí Boko Haram pa àwon àgbè àti àwon ará ìlú ní Borno.

Ókéré jù àwon ènìyàn méèdógún (15) ni a gbó pé àwon agbésùmòmí Boko Haram pa nígbà tí won kolu ara won. Ìròyìn tí Orísun àwon figilanté gbé ni wípé òpò àwon ará ìlú ní won sì ń wá léyìn Ìsèlè ...

Read More »

Wón pa ológun Nàìjíríà kan ní Sambisa lónìí.

Gégé bí olùrànlówó oníròyìn ti ìjoba ìpínlè Sokoto, Imam Imam òsìsé ológun (army officer) M Maiwada àwòrán eni tí ó wà lókè tí ó sèsè di Balogun (captain) ni won yín ìbon pa ní ojú ogun pèlú àwon Boko Haram ...

Read More »

John Nani Pa Olúfà Ńlá, John Nani Tí Ó Jé Konmísónà Ní Ìpínlè Delta. 

 Konmísónà tí ó ń mójú tó àyíká (commissioner of environment), tí a mò sí Hon. Barr John Nani àti àwon emèwà rè kolu tí won sì pa olúfà ńlá tí ó won òsùwòn tí ó tó mítà lónà mérin ó ...

Read More »

Akékòó ilé -èkó Nwafor Orizu College Nsugbe ni àwon omo egbé òkùnkùn yin ìbon pa. 

  Léyìn àrídájú tó ji-n-gí-ri, mo le f’owó s’òyà pé pé ilé-èkó Nwafor Orizu College of Education Nsugbe ti pàdánù tí ó pò .   Arákùnrin Mr Osaji Charles, tí ó jé Mr NASELS télè (2013/2014 session), ni won yín ...

Read More »

Èsì ìdánwò alásekágbá ilé-èkó girama (waec)tí ó burúkú jù nínú odún 2017, tí a rí he. 

Láàrin ogún-l’ógbòn àwon akékòó tí ó tó 1,559,162 tí won jòkó fún ìdánwò àsekágbá ilé -èkó girama tí a mò sí waec ní odún 2017 tí ó jé wípé òpò ni a ti rí, tí ó sì dára … Akékòó ...

Read More »

Ìbon ba àwon ajínigbé nígbà tí won ń dúnà pàsípààrò lówó ní ìjoba ìpínlè Abia. 

Àwon ajínigbé mérin, èyí tí won ti ń da ìpínlè Abia àti agbègbè rè láàmú. Won ti ń gbìyànjú àti parun tí àwon òtelèmúyé so mó Omoba Division ní ojó ketàdínlógún osù keje (19th July ,2017) ní Ovungwu, Isiala -Ngwa ...

Read More »

Ònà tí èèyàn le gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin. (Ways To Deal With An Introverted Wife)

Tí ènìyàn bá wà lábé òrùlé kan náà, ó ye kí won kókó gbà pé ìwà wa kò le b’ára wa mu. Nígbà kan náà o kò ní láti yí enìkejì padà kí o sì jé oníyè ara re. Kódà ...

Read More »

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje àjòdún Washington DC jollof.

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigeria jollof rice) ti kéde gégé bi ipò àkókó nínú ìdíje àjòdún Washington DC jollof. Ní ojó kejì osù keje odún 2017(july 2, 2017) omidan Atinuke Ogunsalu ti Queensway Restaurant &catering in Maryland US, ti se ipò ...

Read More »