Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 72)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Those who have EBO as their weapon has it all.

Ebo doesn’t only solve problems, but Ebo get deep to the cause of the tribulation and solve it from the scratch. Ifa is still listening to prayers like old days. Orunmila still bless like he used to. Esu still accept ...

Read More »

Se eyin tunle di ibo fun Arakunrin yi lekeji ?

Beni abi be ko?    

Read More »

Kini Oruko ogagun yi ?

Read More »

Nje eyin ranti oruko oko ‪yi

kini oruko oko yi ?

Read More »

Foto: Egbo tani eni to joko yi

Tani eni to joko yi

Read More »

Arewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)

Arewa asa wa toni ni Alhaji Taiwo Hassan, abi won ni Ilaro ni odun 1959, baba tobi won ibeji ni, baba tobi baba won ibeji ni, emerin ototo ni won ti bi ibeji ninu ile won,  Won losi ile-we alakobere ...

Read More »

Iwure Owuro Toni: 17-04-­2016

E MAA WI TELE MI : …… *Adun, ayo, idunnu ni temi titi aye *Ire owo, ire omo, ire aiku ni temi. *Apari inu mi ko ni ba tode mi je. *Orisun ayo mi ko ni gbe. *Ise mi ko ...

Read More »

Odo Iwoyi !

A ki gbogbo wa ku ise oni, a si ki wa ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E dakun e wa nkan fidi le abi ki e fi idi le nkan, ki a ...

Read More »

Olobe Lo Loko Soko-Yokoto

Eto Olobe lo loko soko-yokoto ni o gori afefe bayii,,,,,, Adupe lowo olorun fun abo re lori wa, oba ti o pawa mo titi Di ojo oni, a dagbere ni ijejo, atun dupe wipe eledumare ka wa ye loni. Lori ...

Read More »

Ayo Ab’ara Bintin

Ope ni fun Olorun nitori ti o seun ti anu Re duro laelae. Mo layo lati so fun wa wipe Eledua fi Omobinrin lantalanta da ebi kan pataki ninu ilu yi lola. Tii se ebi Olori AJOKE GOLD OLUWAKEMI ti ...

Read More »